Suzzy Teye
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Suzzy Dede Teye | ||
Ọjọ́ ìbí | ọjọ́ kẹfà Oṣù kọkànlá ọdún 2002 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Ghana | ||
Ìga | 1.56 m (5 ft 11⁄2 in) | ||
Playing position | Midfielder | ||
Club information | |||
Current club | Hatayspor | ||
Number | 70 | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2020–2021 | Lady Strikers | ||
2022– | Hatayspor | 13 | (6) |
National team | |||
2018 | Ghana U-17 | 4 | (1) |
2022 | Ghana U-20 | 3 | (0) |
2022– | Ghana | ||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 5 February 2023. † Appearances (Goals). |
Suzzy Dede Teye tí a bí ní ọjọ́ kẹfà Oṣù kọkànlá ọdún 2002 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède Ghana kan, tí ó dúró bí alárinà ní orí pápá fún Hatayspor ní Super League ti Turkey àti ẹgbẹ́ <a href="./Bọọlu_ẹgbẹ_obinrin" rel="mw:WikiLink" data-linkid="117" data-cx="{"adapted":false,"sourceTitle":{"title":"Women's association football","thumbnail":{"source":"https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/b/bd/FIFA_Women%27s_World_Cup_2019_Final_-_Alex_Morgan_and_Stefanie_van_der_Gragt.jpg/80px-FIFA_Women%27s_World_Cup_2019_Final_-_Alex_Morgan_and_Stefanie_van_der_Gragt.jpg","width":80,"height":60},"description":"Association[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] football when played by women","pageprops":{"wikibase_item":"Q606060"},"pagelanguage":"en"},"targetFrom":"mt"}" class="cx-link" id="mwBg" title="Bọọlu ẹgbẹ obinrin">agbábọ́ọ̀lù</a> obìnrin Ghana .
Isé ẹgbẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Teye gbábọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Premier League Women's Ghana Lady Strikers FC . Ní ọdún 2021, wọ́n fún ní orúkọ “Player of the month February”.
Ní Oṣù Kẹẹ̀wá ọdún 2022, ó kó lọ sí Turkey, ó sì buwọ́ lùwé pẹ̀lú Hatayspor láti gbábọ́ọ̀lù ní 2022–23 Sper League .
Isé òkè-òkun
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n gba Teye wọlé sínú ẹgbẹ́ U-17 àwọn ọmọbìrin Ghana láti ṣe eré ní bi [[2018 African U-17 Women's World Cup Qualifying Tournament àti 2018 FIFA U-17 Women's World Cup .
Ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ ti U-20 ti obìnrin Ghana ní bi FIFA U-20 World Cup Women ti ọdún 2022.
Ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ àwọn obìnrin ti orílẹ̀-ède Ghana .
Àwọn ọlá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Olúkúlùkú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Player of the Month: ,(2021 February) Lady Strikers F.C.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "tff0" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "mk" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "aa1" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "gfa1" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "fifa1" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "sna1" defined in <references>
is not used in prior text.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tag with name "dsgh1" defined in <references>
is not used in prior text.
<ref>
tag with name "fgh1" defined in <references>
is not used in prior text.