Jump to content

Sylvester Madu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Sylvester Madu (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kọkànlá oṣù kìíní ọdún 1975) [1] jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Anambra lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2]

Sylvester jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Anambra. Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ kíkà rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ fún ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama kí ó tó kàwé gboyè ní University of Maiduguri, lápá àríwá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Àwọn sinimá àgbéléwò rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò tí ó tó àádọ́ta lé ní igba (250)

Lára àwọn sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa ni;

  • Power of Trust
  • Scent of Passion
  • Holy Cross
  • The Shepherd
  • The Generals
  • Power of Love
  • Tears of the blind
  • Emotional Tears
  • The Cat
  • Ogbanta the family hunter
  • Poverty
  • Scent of Passion
  • Runaway Bride
  • Holy Cross
  • Retaliation
  • Death of Shita Rambo
  • The Family
  • The Illiterate
  • Days of My Wedding
  • Wedding Pandemonium
  • To Love An Angel
  • Different World
  • Tears of the Blind [3]
  • Dangerous Madman
  • Born to Suffer
  • Disclosed
  • The Redeemer

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]