Tòmátò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Tòmátò ní irúgbìn tó po ti o si kéré. Ó da fún ara wa. Tí ó bá ti pón ó ma n pupa, bi ósͅe n pón lósì ma ma tóbi. Orísͅìrisì tòmátò ló wà ní àgbáyé. Wón ma n pe tòmátò ni èso nítorí pé ó ní ìrúgbìn tó pòͅ. Sͅùgbóͅn àwoͅn ènìyàn ma n pé tòmátò l’ágbàye ni èfóͅ, wóͅn sì dèͅ má n se bi èfóͅ.

Tòmátò
Cross-section and full view of a ripe tomato
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
(unranked):
(unranked):
Ìtò:
Ìdílé:
Ìbátan:
Irú:
S. lycopersicum
Ìfúnlórúkọ méjì
Solanum lycopersicum
Synonyms

Lycopersicon lycopersicum
Lycopersicon esculentum

Bí Oúnje[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Tòmátò je eso kan ti a fi maa n se obe. Ti o ba pon tan, kii pe ra nitori naa, awon oloja maa n fe tete ta a tan. Ile Hausa ni gbigbe tòmátò wopo si ju ni ile Naijiria.
Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]