Tóbilọ́ba Àjàyí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tóbilọ́ba Àjàyí
Ọjọ́ìbíOluwatobiloba Ajayi
Eko, Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Oǹkọ̀wé, Agbẹjọ́rò, ajàfẹ́tọ̀ọ́

Tóbilọ́ba Àjàyí jẹ́ Agbẹjọ́rò, ajàfẹ́tọ̀ọ́ abarapá ọmọ Nàìjíríà. Òun náà jẹ́ abarapá ènìyàn fúnrarẹ̀. Ó gba àmìn ẹ̀yẹ Mandela Washington Fellowship lọ́dun 2016. Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí dìgírì kejì nínú ìmọ̀ òfin, International Law láti University of Hertfordshire, ní orílẹ̀-èdè United Kingdom. Lára akitiyan rẹ̀ fún ẹ̀tọ́ àwọn abarapá Ìran 2020 Nàìjíríà fún àwọn abarapá (Nigeria Vision 2020 on disabilities) àti òfin Ìpínlẹ̀ Èkó lórí àwọn abarapá. Ó ti kọ ìwé mẹ́ta.

Ìgbà èwe àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àjàyí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ márùn-ún tí àwọn òbí rẹ̀ bí. Àwọn òbí rẹ̀ lọ́ra láti fi i sí ilé-ìwé nígbà èwe rẹ̀ nítorí pé ó jẹ́ alábarapá. Kò lè jókòó, dúró tàbí rìn lásìkò náà. Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́ta, ó sìn parí ẹ̀kọ́. Ó kẹ́kọ̀ọ́ dé yunifásítì nínú ìmọ̀ òfin kí ó tó dèrò òkè-òkun láti tẹ̀tsiwaju láti kàwé gbàwé ẹri dìgírì kejì, (Masters Degree) ní University of Hertfordshire.[1]

Àwọn akitiyan yàn isẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀, ó ṣiṣẹ́ ní Mobility Aid and Appliances Research and Development Center.[2] Ó kópa nínú ètò Ìran ọdún 2020 fún àwọn abarapá (Nigeria Vision 2020 on disabilities matters), bẹ́ẹ̀ ló wà lára àwọn tí wọ́n kọ̀wé òfin ẹ̀tọ́ àwọn abarapá ní Ìpínlẹ̀ Èkó.[3] She was awarded a Mandela Washington Fellowship in 2016.[4][5]. Lọ́dún 2017, ó ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ As of January 2017 Benola Cerebral Palsy Initiatives.  Títí di February 2018 Ó ṣe àkóso àjọ "Let CP Kids Learn", èyí àjọ tó ń ṣe ìrànlọ́wọ́ àti ìdàgbàsókè àwọn ọmọ abarapá .[6]

Àwọn ṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

{{Reflist} {

  1. Adetorera, Idowu. "‘There is life after disability’". The nation. Retrieved 17 January 2017. 
  2. Adebayo, Bose. "MAARDEC’s Ms wheelchair contest gives voice to the physically challenged". Vanguard. Retrieved 17 January 2017. 
  3. Osonuga, Freeman. "A Nigerian Lawyer With Cerebral Palsy: My Encounter". The Huffington Post. Retrieved 17 January 2017. 
  4. Precious, Drew. "The Presidential Precinct Announces 2016 Mandela Washington Fellows". Presidential Precinct. Retrieved 17 January 2017. 
  5. Precious, Drew. "Tobiloba Ajayi". Presidential Precinct. Retrieved 16 November 2019. 
  6. Dark, Shayera (27 February 2018). "Nigerians with disabilities are tired of waiting for an apathetic government". Bright magazine. https://brightthemag.com/health-nigeria-disability-rights-activism-96aa2cfef5f2. Retrieved 11 November 2019.