T.M. Ilésanmí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ojogbon Thomas Makanjuola Ilesanmi ni eni ti o koko gba oye B.A. ni eka-eko ede ati litireso Aafirika ni Obafemi Awolowo University. O sese fi eyin ti ni aipe yii ni leyin igba ti o ti sise ni eka-eko yii kan naa lati odun 1975 si 2005. Opolopo ise ni ojogbon yii gbe se lori ede Yoruba. Die ninu won ni a ko ni ede Geesi ni isale yii.

Ojogbon T. M Ilesanmi gba ise oluko in Yunifasiti ti Ife(Yunifasiti Obafemi Awolowo, nisinsinyi), Ile-Ife, Naijiria, gegebi Graduate Assistant ni Eka-eko Ede Aafirika ati Litireso ni November 25, odun 1975 leyin igba to ti gboye akeko-jade meji lati Yunifasiti Pontifical, ilu Roomu ati Yunifasiti ti Ife. O gba igbega lenu ise to fi de ipo ojogbon ni osu October, ni odun 1997. Ipo yi ni o wa titi digba ti won fi fi ise sile ni ibamu pelu gbedeke ifisesile ni omo-odun arundilaadorin ni odun 2005.

Bi a ba n wo akojopo ati akosile imo-iwe ojogbon yii, a o rii pe o ni ifokantan ati iteramose. O ti sese di araba ni idi ifi-imo-soro, paapaa, ni eka eko asa Yoruba. Awon iwadii Ojogbon Ilesanmi lori awon ayeye irubọ ati itan ibile se gboogi, won si je itokasi ninu imo isewadii lori Yoruba. Akonimora ati onirele, Ojogbon Ilesanmi ti se agbekale opolopo akosile to je alariyanjiyan, alarojinle ati alakiyesi lori ipede ati ewi Yoruba.

Laaarin akegbe re, Ojogbo Ilesan okan lara awon agba alabojuto fun opo ti o ti se akekoo gboye keji ati oye omowe pelupelu ninu ise -akosile won lori ede ati litireso Yoruba. Awon iwadii ti o jeyo ninu ise-akosile wonyi ni o gba iyi pe won si ferese si ona titun lati ronu ninu eko lori Yoruba.

  • PROFESSOR T.M. ILESAMI AND YORUBA STUDIES