TESCOM Ìpínlẹ̀ Èkó

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

TESCOM Ìpínlẹ̀ Èkó tí ó túnọ̀ sí Teaching Service Commission, jẹ́ àjọ tí ó ń rí sí ètò ìgbanisíṣẹ́ Olùkọ́ ní ìpínlẹ̀ Èkó, ni ó ti fìgbà kan wà lábẹ́ ìṣàkóso Post- Primary Teaching Service Commission (PP- TESCOM) pẹ̀lú oríṣiríṣi àwọn adarí láti ọdún 2004 ṣáájú kí wọ́n tó dá Teachers’ Establishment and Pensions Office (TEPO) sílẹ̀ láti ara (PP-TESCOM) ní ọdún 2005, pẹ̀lú ìbámu ìlànà àti òfin tó làá kalẹ̀ lábẹ́ ìṣàtúntò òfin tó de ètò ẹ̀kọ́ tó dá ẹ̀ka ìṣàkóso ètò ẹ̀kọ́ sílẹ̀ẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 2005, tí ó si fi Tutor General àti Permanent Secretary ṣe adarí fún ẹ̀ka kọ̀ọ̀kan.[1]Èyí wáyé lábẹ́ ìṣàkóso Gómìnà Bọ́lá Ahmed Tinubu tí ó ti fìgbà kan jẹ́ Gómìnà ìpínle Èkó rí.

Ojúṣe àjọ TESCOM[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ojúṣe TESCOM ni láti ma ṣe ètò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ nípa bí a ṣe ń darí, àti bí a ṣe ń ṣàkósó ohun gbogbo fún àwọn Olùkọ́ tí ipò wọn ti tó àkàsọ̀ Kẹtàlélọ́gbọ̀n (Grade Level 13) àti àwọn tí ipò wọn ti ju bẹ́ẹ̀ lọ láti ri wípé ìdánilójú wà wípé wọn yòó lè ṣàkóso, ṣàmúlò ohun tí wọ́n bá ní níkàá wọ́ wọn. [2] Ìgbìmọ̀ àwọn olùkọ́ àgbà àti kékeré tí Won tún jẹ́ òṣìṣẹ́ lábẹ́ àjọ yí ni wọ́n ma ń dára àjọ TESCOM.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Team, Jobgurus. "Lagos State Teaching Service Commission (TESCOM) Massive Recruitment 2019 Jobs in Nigeria". Jobgurus Services. Retrieved 2019-12-15. 
  2. Kehinde, Opeyemi (2019-11-13). "Teaching jobs: Lagos TESCOM website remains inaccessible 14 hours after application opens – Daily Trust". Daily Trust. Archived from the original on 2019-12-15. Retrieved 2019-12-15. 
  3. "Teaching Service Commission, TESCOM". Teaching Service Commission, TESCOM. Retrieved 2019-12-15.