Taaooma

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Taaooma
Ọjọ́ìbíMaryam Apaokagi
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaKwara State University
Iṣẹ́Comedian
Olólùfẹ́
Abula (m. 2021)

Maryam Apaokagi, tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Taaooma, jẹ́ apanilẹ́rìn-ín orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó tún jẹ́ ayàwòrán[1] Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, òun ni olùdarí àti olùdásílẹ̀ Chop Tao,[2] èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ oúnjẹ, ó sì ń darí ilé-iṣẹ́ Greenade [2] Ó di gbajúgbajà látàrí àwo eré apanilẹ́rì-ín rẹ̀ lórí ẹ̀rọ ayárabíàṣá.[3][4]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀.[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Maryam Apaokagi ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì, ọdún 1999 sí ìlú rẹ̀ ní Ilorin, Ìpínlẹ̀ Kwara, àmọ́ ó lo ìgbà èwe rẹ̀ ní Namibia. Ó kékọ̀ọ́ nípa Tourism and Travel Service Management ní Kwara State University.[5][6][7] Ní ọdún 2022, ó sọ fún ìwé-ìròyin The Punch pé, “mo fẹ́ di dọ́kítà, mo sì tún yí i padà sí agbẹjọ́rò. Àmọ́ ẹ̀kọ́ tourism ni wọ́n fún mi láti lọ kọ́ ní ilé-ìwé”.[8]

Ìgbésí ayé rè.[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní oṣù kẹwàá, ọdún 2020, wọ́n fi Apaokagi fún ọkọ àfẹ́sọ́nà rẹ̀, tí í ṣeAbdulaziz Oladimeji (tí a tún mọ̀ sí. Abula) ní Namibia,[9] wọ́n sì ṣe ìgbeyàwó ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kìíní, ọdún 2021.[10][11]

Àtòjọ àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Award Category Result Ref.
2019 The Gage Awards Best Online Comedian Of The Year Gbàá [12]
2020 Nigeria's 25 under 25 awards Social Entrepreneur Gbàá [13]
The Future Awards Africa style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé [14]
Maya Awards (Africa) style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé [15]
City People Music Awards style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
The Guardian 100 Most Inspiring Women in Nigeria Àdàkọ:Shortlisted [16]
2021 Net Honours style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé [17]
JCI TOYP Award Cultural Achievement Gbàá [18]
2022 Africa Magic Viewers' Choice Awards style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé [19]
The Future Awards Africa style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé [20]
Net Honours style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé [21]

Tún wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "How video editing made me Taaooma, the comedienne – Maryam Apaokagi". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-07-11. 
  2. 2.0 2.1 "Maryam Apaokagi (@taaooma)". Culture Intelligence from RED. Archived from the original on 5 July 2022. Retrieved 5 July 2022. 
  3. "How two Nigerian women are breaking into comedy's boys club". Christian Science Monitor. 10 August 2020. Retrieved 8 October 2020. 
  4. "Who is Taaooma? Unmasking Instagram's unlikely most popular comedian [Pulse Interview]". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-02-18. Retrieved 2021-03-01. 
  5. "Comedian Taaooma hits 1m on Instagram, watch how she marks it". P.M. News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-05-16. Retrieved 2021-03-01. 
  6. "Taaooma talks about growing up in Namibia, relationship, popularity and how she switches her roles" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-03-01. 
  7. ""My momsy no dey beat me" - Taaooma". BBC News Pidgin. 2020-04-03. Retrieved 2021-03-01. 
  8. Edeme, Victoria (12 May 2022). "My mum inspires some of my skits, says Taaooma". Punch Newspapers. Retrieved 5 July 2022. 
  9. "Video: Taaooma, Abula share their engagement story". P.M. News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-10-30. Retrieved 2021-03-01. 
  10. "PHOTOS: Taaooma marks first wedding anniversary". TheCable Lifestyle. 24 January 2022. Retrieved 27 March 2022. 
  11. Ukonu, Ivory; THEWILL (2022-02-06). "2021 Was A Great Year For Me – Maryam Apaokagi-Greene" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-21. 
  12. "WINNERS FOR THE GAGE AWARDS 2020 | GAGE AWARDS". Gage Awards. Archived from the original on 27 March 2020. Retrieved 8 October 2020. 
  13. Udeh, Onyinye (28 August 2020). "Kiki Osinbajo, Taaooma, Kumi Juba, Captain E, Sydney Talker Others nominated for Nigeria's 25 under 25 Awards. » YNaija". YNaija. Retrieved 8 October 2020. 
  14. "The Future Awards Africa: Class of 2020". November 8, 2020. Archived from the original on October 24, 2021. Retrieved January 20, 2023. 
  15. "Mayorkun, Taaooma, Lolade Abuta tops 2020 MAYA AWARDS AFRICA Nominees' List". September 28, 2020. Archived from the original on December 2, 2022. Retrieved January 20, 2023. 
  16. "Leading ladies Africa – 100 Most inspiring women in Nigeria 2020". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-03-14. Retrieved 2021-03-01. 
  17. "Net Honours - The Class of 2021". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-07. 
  18. Olowoporoku, Muhamin. "Taaooma, Asisat Oshoala, others to receive JCI TOYP award". P.M. News. Retrieved 5 July 2022. 
  19. "2022 Africa Magic Awards Nominees don land- See who dey list". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-60818021. 
  20. "See who win for The Future Awards 2022". BBC News Pidgin. Retrieved 27 March 2022. 
  21. Bakare, Simbiat (2 July 2022). "NET Honours 2022: Ikorodu Bois Beats Mr Macaroni, Sabinus to Win 'Most Popular Comedian'". Nigerian Entertainment Today. Retrieved 5 July 2022.