Jump to content

Tafseer-e-Majidi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tafseer-e-Majidi
Cover of Urdu Version
Olùkọ̀wéAbdul Majid Daryabadi
Àkọlé àkọ́kọ́Tafsirul Quran: Ògbufọ̀ àti ìdásí tí ìwé mímọ́ Quran
CountryIndia
LanguageEnglish & Urdu
SubjectTafsir
GenreModern
Publication date
1941
Media typePrint
ISBNÀdàkọ:ISBNT The Islamic Foundation Bangladesh Version
OCLC17557958
297.1227
LC ClassBP.109 1981B

Tafseer-e-Majidi tàbí Tafsirul Quran: Ògbufọ̀ àti ìdásí tí ìwé mímọ́ Quran (Urdu: القرآن الحکیم) a complete TafsirAbdul Majid Daryabadi kọ̀.[1][2] Ó ṣe àwòkọ́ṣe Ashraf Ali Thanwi tí ó kọ Tafsir tí ó sì kọ́kọ́ kọ Tafsir yìí nígbà náà ní èdè Gèésì lẹ́yìn náà ní èdè in Urdu.[3] Ètò àti àgbékalè Urdu tí wọ́n ṣàmúlò fún kíkọ Tafsir yìí náà ni ti Tafsir èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ìyàtọ̀ kan tí ó wà ní pé Tafsir yìí yẹ kí ó kún kí ó sì gùn.[4] Òǹkọ̀wé fúnra rẹ̀ ló kọ Ọ̀rọ̀ àkọ́sọ ní oṣù Kejìlá ọdún 1941.[5] Òǹkọ̀wé náà ṣàkíyèsí pé láti ṣògbufọ̀ Quran jẹ́ ohun tí ó le lọ́pọ̀lọpọ̀. Nítorí náà, ó gba àwọn Ògbufọ̀ níyànjú láti tẹ̀lé àwọn kókó mẹ́fà tí jẹ́ gbòógì àti àwọn oríṣi kókó mìíràn láti tú Quran sí èdè Gẹ̀ẹ́sì. Nítorí pé ó ṣe àkíyèsí àwọn ìṣòro ògbufọ̀ nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì ó sì sọ pé, kò sí èdè náà lágbàáyé bíi Arabic. Abul Hasan Ali Hasani Nadwi ni ó kọ ìfáàrà ni ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹ́jọ ọdún 1981.[5] Daryabadi ṣiṣẹ́ láti wo àwọn iṣẹ́ ìwádìí, tí wọ́n ṣe ní West tàbí East kọjá tàbí ní ayé òde òní, èyí tí ó kọ̀nfáàmù àwọn ẹṣẹ Quran náà tí ó tọ́ka wọn sí exegesis rẹ̀.[6]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Chapter 8". Ìtumọ̀ Quran ní Urdu : ẹ̀kọ́ tí ó gbépọn. Nazeer Ahmad Ab Majeed, Aligarh Muslim University. K̲h̲alīq Aḥmad Niz̤āmī Markaz-i ʻUlūmulqurʼān. New Delhi. 2019. ISBN 978-93-89166-89-7. OCLC 1124776298. https://www.worldcat.org/oclc/1124776298. 
  2. Usmani, Taqi (2005) (in ur). Tabsre. Pakistan: Maktaba Ma'ariful Quran. pp. 177. https://archive.org/details/Tabsre_201610. 
  3. Mabood 2019, p. 34.
  4. Àdàkọ:Cite thesis
  5. 5.0 5.1 Mabood 2019, p. 45.
  6. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :ir