Jump to content

Taiwo Rafiu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Taiwo Rafiu tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún Osù Kẹ̀fà ọdún1972 ní Ìpínlẹ̀ Èkó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá sínú agbọ̀n obìnrin ti ilẹ̀ Nàìjíríà. [1] Ó lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti Ìlú Oklahoma ní Amẹrika pẹ̀lú ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá sínú agbọ̀n ti àwọn obìrin ti orílẹ̀-ède Nàìjíríà ní bi 2004 Summer Olympics.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]