Taiye Selasi
Taiye Selasi | |
---|---|
Selasi at the Erlanger Poetenfest, 2013 | |
Ọjọ́ ìbí | Taiye Selasi 2 Oṣù Kọkànlá 1979 London, United Kingdom |
Iṣẹ́ | Novelist |
Alma mater | Yale University; Nuffield College, Oxford |
Ìgbà | 2005–present |
Literary movement | Realism, Drama |
Website | |
Taiye Selasi lórí Twitter |
Taiye Selasi (bíi ni ọjọ́ kẹji oṣù kọkànlá ọdún 1979) jẹ́ akọ̀wé àti ayàwòrán.[1][2]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Taiye sì ìlú London, òun sì ni àkọ́bí nínú ìbejì tí àwọn òbí rẹ bí.[3] [4]Ìyá rẹ̀, Dr. Juliette Tuakli, jẹ́ oníṣègùn ni orílẹ̀ èdè Ghana,[5][6] bàbà rẹ, Dr. Lade Wosornu, sì jẹ́ dókítà ni ilẹ̀ Saudi Arabia.[7][8][9] Taiye gboyè akẹ́kọ̀ọ́ to tayọ julọ ni Yale University. Ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Nuffield College.[10]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2005, ìwé ìròyìn tí The Lip ṣe atẹjade iṣẹ́ rẹ̀ tí ó pè àkòrí rẹ̀ ni Bye-Bye.[11][12][13][14] Ní ọdún 2006, ó kọ ìwé nípa àwọn ọmọbìnrin ni ilẹ̀ Áfríkà, ó sì pe àkòrí rẹ ni The Sex Lives of African Girls.[15] Ní ọdún 2010, Ann Godoff ra ìwé Taiye tí àkòrí rẹ jẹ Ghana must Go, ó sì ṣe atẹjade rẹ̀ ni ọdún 2013.[16][17][18][19][20][21][22] Ni ọdún 2013 àti 2014, wọn fi sì àárín àwọn akọ̀wé ọ̀dọ́ tí ó dára jù lọ.[23] Ni ọdún 2012, òun àti David Adjaye jọ ṣètò ilé ìkàwé tí Gwangju River Reading Room.[24] Ní ọdún 2015, Selasi farahàn sì ayẹyẹ tí wọn má ṣe fún àwọn òn kọ̀wé ni orílẹ̀ èdè Iceland, Iceland Writers Retreat, ó sì jẹ́ ìkan laarin awọn tó sọ̀rọ̀.[25]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Lewis, Tim (22 March 2013). "Taiye Selasi: 'I'm very willing to follow my imagination'". The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/books/2013/mar/22/taiye-selasi-interview-ghana-must. Retrieved 2019-03-27.
- ↑ Selasi, Taiye (22 March 2013). "Taiye Selasi on discovering her pride in her African roots". The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/books/2013/mar/22/taiye-selasi-afropolitan-memoir. Retrieved 2019-03-27.
- ↑ Virginia Vitzthum, "The Fascinator: Taiye Selasi", Elle, 15 March 2013.
- ↑ "Family matters: how novelist Taiye Selasi came to terms with her very modern family", London Evening Standard, 5 April 2013.
- ↑ "Dr. Juliette Tuakli, Child and Reproductive Health, University of Ghana, Legon.The Bill and Melinda Gates Institute for Population and Reproductive Health
- ↑ "Juliette Tuakli". Jhsph.edu. Archived from the original on 14 December 2012. Retrieved 31 March 2011. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Prof. Lade Wosornu" Archived 2017-05-21 at the Wayback Machine., University of Dammam.
- ↑ "Lade Wosornu". 9 September 2009. Retrieved 31 March 2011.
- ↑ "Prof. Lade Wosornu Compiles His Articles into A Book". The Ghanaian Times. Archived from the original on 23 August 2011. https://web.archive.org/web/20110823060853/http://newtimes.com.gh/story/1165. Retrieved 31 March 2011.
- ↑ "Taiye Selasi", Ghana Rising, 25 February 2012.
- ↑ Taiye Selasi, "Bye-Bye, Babar", The LIP Magazine, 3 March 2005.
- ↑ Bady, Aaron, and Taiye Selasi. "From That Stranded Place." Transition 117 (2015): 148. Web.
- ↑ Gehrmann, Susanne. "Cosmopolitanism With African Roots. Afropolitanism's Ambivalent Mobilities". Journal of African Cultural Studies 28.1 (2015): 61-72. Web.
- ↑ Stefanie Cohen, "Growing Up With a Panther Mom", The Wall Street Journal, 28 February 2013.
- ↑ "Interview: Taiye Selasi", Granta, 10 June 2011
- ↑ Diana Evans, "Ghana Must Go by Taiye Selasi – review", The Guardian, 3 April 2013.
- ↑ Margaret Busby, "Ghana Must Go, By Taiye Selasi" (review), The Independent, 29 March 2013.
- ↑ "A singular voice", The Economist, 16 March 2013.
- ↑ Sam Sacks, "An Auspicious How-Do-You-Do", The Wall Street Journal, 1 March 2013.
- ↑ Molly Fischer, "Penguin Press Buys First Novel with Salman and Toni’s Seal of Approval" Archived 2010-06-15 at the Wayback Machine., New York Observer, 14 June 2010.
- ↑ "The WSJ Best Fiction of 2013", The Wall Street Journal, 13 December 2013.
- ↑ "Books of the year: Torrents of words", The Economist, 5 December 2013.
- ↑ Granta 123: Best of Young British Novelists 4, Spring 2013.
- ↑ "david adjaye & taiye selasi: gwangju river reading room", designboom, 20 December 2013.
- ↑ "IWR 2015". Iceland Writers Retreat (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-06-07. Archived from the original on 2020-02-13. Retrieved 2020-02-13.