Tajudeen Oyèwọlé (Abìjà)
Ìrísí
Tajudeen Oyèwọlé tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Abìjà ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù Kẹwá , ọdún 1957.[1][2]Jẹ́ gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá àgbéléwò, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó sábà ma ń kópa nínú eré sinimá gẹ́gẹ́ bí ògbójú babaláwo àti oníṣègùn tó gbóná tí ó sì ma ń fi agbára rẹ̀ gba àwọn ènìyàn sílẹ̀ nínú eré.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Vetean Actor, Tajudeen Oyewole "Abija" Battles Extreme Poverty, Begs For Sponsors To Perform Hajj In Mecca". Within Nigeria. 2018-08-19. Retrieved 2020-01-20.
- ↑ "I always kneel to beg my husband anytime he is angry - Abija’s wife". Abija’s wife – Punch Newspapers. 2015-12-15. Retrieved 2020-01-19.
- ↑ Badmus, Kitan (2015-08-12). "Veteran Yoruba Actor, Abija, Confirms He Is Living In Poverty, Cries Out For Help » Thesheet.ng". Thesheet.ng. Archived from the original on 2016-06-10. Retrieved 2020-01-20.