Tajudeen Yusuf
Ìrísí
Tajudeen 'TeeJay' Yusuf | |
---|---|
Member of the House of Representatives of Nigeria representing Kabba/Bunu/Ijumu | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 2011 | |
Asíwájú | Dino Melaye |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 25 August 1968 |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | PDP |
Alma mater | University of Jos |
Profession | Politician |
Website | https://www.yusufteejay.org/ |
Tajudeen Yusuf ti gbogbo ènìyàn mọ si "TeeJay" (ti a bi ni 25 August 1968) jẹ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà lati ègbè òṣèlú Peoples Democratic Party . [1] [2] O soju agbegbe Kabba/Bunu/Ijumu ni ile ìgbìmọ̀ aṣòfin ti orílè-èdè Naijiria, ipo ti won dibo fun ni ọdún 2011. [3] [4] O jẹ alaga iṣaaju, Igbimọ Ile lori Ọja Olu ati Awọn ile-iṣẹ. [5]
abẹlẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Hon. TeeJay lọ si ile-ẹkọ giga St Augustine's College Kabba, nibiti o ti gba Iwe-ẹri Ilé-ìwé Iwọ-oorun Afirika/GCE ni ọdun 1987. Ni odun 1997, o gboye nípa ìmò eto oro ajé lati Fasiti ti Jos, Ìpínlẹ̀ Plateau. [6]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.shineyoureye.org/person/yusuf-ayo-tajudeen
- ↑ https://www.blueprint.ng/in-kogi-pdps-tajudeen-yusuf-wins-reps-seat/
- ↑ https://accountablenigeria.org/?q=profile/hon-tajudeen-ayo-yusuf
- ↑ https://citizensciencenigeria.org/public-offices/persons/tajudeen-ayo-yusuf
- ↑ https://www.vanguardngr.com/2018/08/securities-exchanges-association-will-deepen-capital-market-sec-dg/
- ↑ https://yusufteejay.org/bio/[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]