Taraji P. Henson

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Taraji P. Henson
Taraji P. Henson 2011.jpg
Henson at the 2011 Heart Truth fashion show
Ọjọ́ìbíTaraji Penda Henson
Oṣù Kẹ̀sán 11, 1970 (1970-09-11) (ọmọ ọdún 52)
Washington, D.C., U.S.
Iṣẹ́Actress, singer
Ìgbà iṣẹ́1997–present
Àwọn ọmọ1

Taraji Penda Henson (ojoibi September 11, 1970) je osere ati akorin ara Amerika. o gbajumo fun ere re bi Yvette ninu filmu Baby Boy (2001), Shug ninu Hustle and Flow (2005) ati Queenie ninu The Curious Case of Benjamin Button (2008), eyi ti won pe loruko fun Ebun Akademi fun Obinrin Osere Akopa Didarajulo ni 2009. Lati 2011, o ti unkopa ninu ere drama ori telifisan CBS Person of Interest.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]