Tayo Oviosu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tayo Oviosu
Oviosu far left in 2018
Ọjọ́ìbíEyitayo David Oviosu
Oṣù Kẹ̀sán 10, 1977; ọdún 46 sẹ́yìn (1977-09-10)
Orílẹ̀-èdèNigerian, American
Ẹ̀kọ́Electrical and Electronics Engineering, University of Southern California
Master's degree in Business Administration, Graduate School of Business, Stanford University.
Iṣẹ́Entrepreneur
Ìgbà iṣẹ́2009–present
Gbajúmọ̀ fúnFounder and Group CEO of Paga
TitleGroup CEO of Paga
Olólùfẹ́
Affiong Williams (m. 2014)
Websitepaga.com/

Tayo Oviosu jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, tó jẹ́ oníṣòwò, tó tún ṣèdásílẹ̀ Paga, èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tó fàyè gba sísan owó láti orí ẹ̀rọ-alágbèéká wa. Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni Paga kọ́kọ́ gbòde.[1][2][3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Tara Fela-Durotoye, Tayo Oviosu, Funke Bucknor & more! We present the 10 most powerful Under-40s in Business - #YNaijaPowerList » YNaija". YNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-03-31. Retrieved 2019-05-24. 
  2. "21 Nigerian Tech CEOs at the Top of Their Game". TechCabal (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-04-15. Retrieved 2019-05-24. 
  3. touch, Chief Chronicler Get in (2017-04-10). "Meet Tayo Oviosu, the man whose financial services company has wider reach than all banks in Nigeria combined". Techpoint.Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-05-24.