Jump to content

Teddy Pendergrass

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Teddy Pendergrass
Background information
Orúkọ àbísọTheodore DeReese Pendergrass
Ìbẹ̀rẹ̀Philadelphia, Pennsylvania, USA
Irú orinR&B, soul, gospel, jazz
Occupation(s)Singer, songwriter, composer
InstrumentsVocals, piano, guitar, drums
Years active1970–2006
LabelsPhiladelphia International
Asylum
Elektra
Surefire/Wind Up
Associated actsHarold Melvin & The Blue Notes
WebsiteOfficial site

Theodore DeReese "Teddy" Pendergrass, Sr. (March 26, 1950[1] – January 13, 2010[2]) je akorin R&B/soul ara Amerika. Pendergrass koko gbajumo gege bi akorin asiwaju egbe olorin Harold Melvin & the Blue Notes ninu awon odun 1970 koto bere sini da korin nipari ewadun na. Ni odun 1982 o ni ipalara gidi leyin ijamba oko ni Philadelphia eyi fa iyaro re lati ibadi de sale.

Igba ewe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

O je bibi gege bi Theodore DeReese Pendergrass ni Kingstree, South Carolina ni Amerika, omo Jesse Pendergrass ati Ida Geraldine Epps. Nigba ewe Pendergrass, baba re fi ebi re sile ko to ku ni 1962. Lodun melo leyin eyi ni won ko lo si Philadelphia ibi ti Theodore to lo si Thomas Edison High School for Boys. O je omo egbe akorin Edison Mastersingers. Leyin eyi lo fi ile-eko sile[3] fun ise orin. Gege bi olukowe Robert Ewell Greene se so Pendergrass di alufa nigba ewe re. Ko pe sigba yi lodi onilu ati akorin fun egbe akorin.

Ise orin[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Pendergrass bere ise orin gege ni onilu fun The Cadillacs ki won o to darapo mo Harold Melvin & the Blue Notes. Nigbati Pendergrass fi egbe akorin Harold Melvin & the Blue Notes sile leyin ijiyan pelu Harold Melvin, o bere si ni dakorin o si gbe awo-orin bi "The More I Get the More I Want," "Close the Door," "I Don't Love You Anymore," "Turn Off the Lights" ati awon miran jade.[1]

Awo-orin to koko da gbejade ni akole Teddy Pendergrass (1977), eyi to tele ni Life is a Song Worth Singing (1978), Live Coast to Coast ati Teddy (1979), TP (1980) ati It's Time for Love (1981).[1] O tun korin pelu Whitney Houston ninu orin "Hold Me" lati awo-orin Houston.

Awon awo-orin[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • 1977: Teddy Pendergrass
 • 1978: Life Is a Song Worth Singing
 • 1979: Teddy
 • 1980: TP
 • 1981: It's Time for Love
 • 1982: This One's for You
 • 1983: Heaven Only Knows
 • 1984: Love Language
 • 1985: Workin' It Back
 • 1988: Joy
 • 1991: Truly Blessed
 • 1993: A Little More Magic
 • 1997: You and IItokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]