Jump to content

Teniola Aladese

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Teniola Aladese
ÌbíLagos State
Iṣẹ́Actress
Producer
Casting director

Teniola Aladese jẹ́ òṣèrébìnrin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, aṣàgbéjáde eré àti olùdarí eré.

Ìgbésí ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Téníọlá Aládaṣe sí ìpínlẹ́ Èkó, ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa Mass Communication ní Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Covenant.[1]

Iṣẹ́-ṣíṣe rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Teniola Aladese ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi alábòójútó aṣàgbéjáde fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù àgbéléwò láàárín ọdún 2013 sí 2015.[2] Ó di olókìkí lẹ́yìn tó ṣe ẹ̀dá-ìtàn Akweyon nínú fíìmù àgbéléwò 'Jemeji' nínú èyí tí ó tún jẹ́ aṣàgbéjáde eré náà.[3] Ní ọdún 2015, ó fara hàn nínú Perfectly Flawed.[4] Ní ọdún 2018, o jẹ́ olùpilẹ̀ṣẹ̀ ọ̀rọ̀ ẹnu àwọn ẹ̀dá-ìtàn kọ̀ọkan fún "Forbidden"[5]

Year Title Role Ref
2022 Loving Amanda [6]
2021 Soólè [7]
2021 Superstar [8][9]
2021 Little Black Book [10]
2021 Ricordi [10][11]
2020 Unbroken Folasade ‘FK’ Kuku [12][5]
2020 Finding Hubby Tosan [10][12]
2020 Lara of Lagos Lara [13][14]
2018 Jemeji Akweyon [15][16]
2015 Perfectly Flawed [17]

Àwọn àmì-èyẹ tó ti gbà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Aladese ni wọ́n yàn fún àmì-ẹ̀yẹ ti The Future Awards Africa, fún ẹ̀bùn eré ṣíṣe.[18][19] Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Trailblazer ní ọdún 2022, lórí Africa Magic Viewers' Choice.[20][21]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Teniola Aladese". IMDb. 2023-03-07. Retrieved 2023-03-07. 
  2. Thomas-Odia, Ijeoma (2022-05-28). "Teniola Aladese: As far back as SS2, I knew I wanted to act". The Guardian Nigeria News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-14. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "I’ve a beautiful car but driving scares me to death– Teni Aladese". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-22. Retrieved 2022-04-13. 
  4. ""I’ve laughed. I’ve cried. I’m still puzzled" – Teniola Aladese Couldn’t Believe She Won An AMCVA". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-05-16. Retrieved 2022-07-14. 
  5. 5.0 5.1 "Meet Teniola Aladese Is The Next Big Thing To Happen To Nollywood" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-06-13. Retrieved 2022-04-13. 
  6. "Loving Amanda: Chukwujekwu, Aladese, Arubayi, Adeoye to feature in New Movie". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-01-29. Retrieved 2022-04-15. 
  7. "Kayode Kasum Uncovers Exciting Teaser for ‘Soòlé’". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-16. Retrieved 2022-04-13. 
  8. "TEASER: Nancy Isime, Timini Egbuson star in romantic drama 'Superstar'". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-11-05. Retrieved 2022-04-13. 
  9. "Inkblot Productions to host 10-Year anniversary gala, premiere 'Superstar' movie" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-12-20. Retrieved 2022-04-13. 
  10. 10.0 10.1 10.2 Ajetunmobi, Maymunah (2021-03-24). "Teniola Aladese and 9 other Nollywood actresses to watch out for in 2021". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-13. 
  11. Nwogu, Precious 'Mamazeus' (2021-02-11). "Watch the official trailer for 'Ricordi' web series". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-13. 
  12. 12.0 12.1 Alao, Biodun (2022-01-11). "50 English Actresses To Watch Out For This Year". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-15. 
  13. "Lara Of Lagos Set To Hit Screens With A Bang". Independent Newspaper Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-15. 
  14. Nwogu, Precious 'Mamazeus' (2020-07-09). "'Lara of Lagos' is coming this July! Watch teaser". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-15. 
  15. "The gift of Jemeji". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-11. Retrieved 2022-04-13. 
  16. izuzu, chibumga (2017-06-08). "Who is your favourite character on "Jemeji"?". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-13. 
  17. "Teniola Aladese". IMDb. July 21, 2022. Retrieved July 21, 2022. 
  18. "Full list: Tems, Bimbo Ademoye win at The Future Awards Africa 2022". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-02-20. Retrieved 2022-04-13. 
  19. "See who win for The Future Awards 2022". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-60454375. 
  20. "Stan Nze, Osas Ighodaro win big - Full list of all di winners from 2022 AMVCA". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-61452928. 
  21. "Full list of AMVCA 8 winners - The Nation Newspaper" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-05-15. Retrieved 2022-05-15.