Tereza Master

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Tereza Master (ti a bi ni ọjọ kankanlelogun Oṣu Kẹsan ọdun 1988) jẹ asare jinjinna ara orilẹ-ede Malawi kan ti o je ojogbon ni ere-ije . O dije ninu idije ere-ije obinrin ni Olimpiiki Igba ooru 2016 nibiti o ti pari ni ipo 98th pẹlu akoko 2:48:34, itan titun fun orilẹ-ede kan .

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ita ìjápọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Tereza Master at Olympics at Sports-Reference.com (archived)