Terra Kulture

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Terra Kulture

 

Terra Kulture jẹ ilé àwòrán ati aṣa ni ìpínlè Eko tí o sì ni ilé oúnje ninú rè. [1]

Idasile[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Agbẹjọro Naijiria Bolanle Austen-Peters ni o da Terra Kulture silẹ ni ọdun 2003. [2]

Bolanle Austen Peters ní TerraKulture ní ọjọ́ kẹta, oṣù kìíní ọdún 2022 ní ibi àfihàn "Death and the King's Horseman"

Ní arin ilé naa jẹ ile ounjẹ wà àti ile ti a un kó àwon iwe ati nkan aṣa sí pèlú ilé awon aworan iyebiye ní Naijiria, [3] ilé ìtàgé tún wà níbè, [4] ati awọn iwe ní èdè méta to gbajumo jù ni Nàìjíríà, Hausa, Ibo . àti Yorùbá .

Ni ipade odoodun, wón ma ún ta àwon aworan iyebiye [5]

Terra Arena[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Terra Kulture ṣe ifilọlẹ ilé itage re, Ó le gba ènìyàn 450, a si ún pe ibè ní Terra Kulture Arena, ti o wa ni olu-iṣẹ rẹ Tiamiyu, Savage Crescent, Victoria Island, ìpinlè Eko, Nàìjíríà.

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]