Jump to content

Teslim Balogun Stadium

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Main-bowl-teslim-balogun-stadium-surulere-lagos

Papa isere Teslim Balogun jẹ papa iṣere ni Surulere, Lagos, Nigeria . A ún julọ fun ere bọọlu afesegba, o si jé ilé fún àwon egbé agbábolù First Bank FC. Ẹgbẹ agbabọọlu rugby orilẹede Naijiria tun lo papa isere naa. [1] Papa iṣere naa le gba eniyan 24,325, won si un lo fún boolu afesegba orílè-èdè sí orílè-èdè O wa legbe papa iṣere ti ìpínlè Eko.

A só pápá ìseré náà loruko Teslim Balogun, eni to jé agbábolù télèrí. A bèrè si ún ko ní odun 1984 lábé isejoba Gomina ologun Gbolahan Mudasiru, a si parí kíko rè ni odun 2007, owó kíkó rè jé #1.3billion.[2]

Eyo Festival, Teslim Balogun Stadium, 2011

Boolu ifesegba àkókò tí a gbá ni pápá náà wáyé ni odunkan náà laarin egbé Enyimba ti Nàìjíríà àti Asante Kotoko. Oluyaworan O.C Majoroh ló yaworan pápá náà.[3]

  1. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2019-07-15. Retrieved 2022-09-10. 
  2. "Teslim Balogun Stadium, Lagos". cityseeker. Retrieved September 10, 2022. 
  3. "TESLIM BALOGUN STADIUM SURULERE LAGOS". Glimpse Nigeria. August 16, 2021. Archived from the original on September 10, 2022. Retrieved September 10, 2022.