The Beat 99.9 FM

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Beat 99.9 FM jẹ́ ilé-iṣẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ èlédè-Gẹ̀ẹ́sì tí ó kalẹ̀ sí ìlú Èkó èyí tí ó dá lórí orin, àlàyé àti ilé-iṣẹ́ eré ìdárayá Nàìjíríà. Ilé-iṣẹ́ náà bẹ̀rẹ̀ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní Ọjọ́ Kìn-ín-ní Oṣù Keje, Ọdún 2003.[1] Nípasẹ̀ ilé-iṣẹ́ yìí kan náà ni Beat TV, ìkànnì orí YouTube fi wà. [2][3] Beat FM jẹ́ ilé-iṣẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ àkọ́kọ́ ní Áfíríkà tó kọ́kọ́ gba àmì-ìdánimọ̀ ní orí Twitter. [4][5]

Àwọn Agbóhùsáfẹ́fẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ti Lọ́wọ́lọ́wọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn ti Tẹ́lẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Dami Elebe

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Daniel O./Jiggaz (3 February 2014). "An Open Letter To The Beat 99.9FM". yabaleftonline.com. Retrieved 11 March 2017. 
  2. "About Us | The Beat 99.9 FM". Thebeat99.com. Archived from the original on 2014-02-06. Retrieved 2014-02-04. 
  3. "The Beat FM". Archived from the original on 17 May 2014. Retrieved 15 May 2014. 
  4. "The Beat FM gets verified on Twitter". thenet.ng. Retrieved 15 May 2014. 
  5. "The Heartbeat of Lagos | The Beat 99.9 FM". Thebeat99.com. 2013-10-18. Retrieved 2014-02-04.