The Cosby Show

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Infobox Television

The Cosby Show ni ere alawada ori telifisan ni Amerika pelu Bill Cosby, to koko jade sori afefe ni September 20, 1984 to si wa ni be fun odun mejo lori ile-ise telifisan NBC titi di April 30, 1992. Ere na da lori ebi Huxtable family, ti wo je ebi omowe omo Afrika Amerika ti won gbe ni Brooklyn, New York.
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]