This Day
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti ThisDay)
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa the Nigerian newspaper. Fún ìtumọ́ míràn, ẹ wo: This Day (ìṣojútùú).
THISDAY LOGO.png | |
Type | Daily newspaper |
---|---|
Format | Broadsheet |
Owner | Nduka Obaigbena |
Publisher | Leaders & Company Ltd. |
Founded | Oṣù Kínní 22, 1995 |
Language | English |
Headquarters | Apapa, Lagos |
Official website | Àdàkọ:Official URL |
This Day jẹ́ òkan lára àwon ìwé-ìròyìn olójoojúmọ́ ní orílẹ̀-èdè Naijiria. A tẹ ìwé iroyin THISDAY jáde fún ìgbà àkọ́kọ́ ní ọjọ kejìlélógún oṣù kínní, ọdún 1995 (22 January 1995).[1] Olú iléeṣẹ́ rẹ̀ wà ní ilú Apapa, ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Olùdásílẹ̀ ilé-isé ìròyìn náà ni Nduka Obaigbena, òun ni alága ẹgbẹ́ THISDAY media àti ìkànnì ìròyìn ARISE.
THISDAY ni ilé-isé méta fún ìte iroyin, wón wà ní Abuja, Èkó àti Asaba, àwon ni ilé iwe-iroyin tí ó kókó lò inki aláwò ní Nàìjirià [2]
Àwon Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "About Us". THISDAYLIVE. 2016-02-26. Retrieved 2022-04-29.
- ↑ Otufodunrin, Lekan; Network, Media Career Development; Adeniyi, Esther; Udom, Emmanuel; Development, Media Career (2020-02-10). "THISDAY @ 25: Success story, impact, low points". Media Career Services. Archived from the original on 2020-02-17. Retrieved 2022-04-29.