Thishiwe Ziqubu
Thishiwe Ziqubu | |
---|---|
Thishiwe Ziqubu n soro nipa sise oludari MTV Shuga ni odun 2019 | |
Ọjọ́ìbí | 5 August 1985 |
Orílẹ̀-èdè | South Africa |
Iṣẹ́ | oludari ere ati osere |
Thishiwe Ziqubu (ti a bi ni ojo karun osu kejo odun 1985) je ako ere, oludari ere ati osere ti owa lati ilu South africa.[1] Won gba ami eye Best Actress in a Supporting Role ni 2016 Africa Movie Academy Awards , fun ipa won gege bi Tashaka ninu ere ife Tell Me Sweet Something.[2] Ni odun 2019, won shey oludari awon ipele kankan ninu MTV Shuga Down South [3]
Eko
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ziqubu keko nipa kiko ere ati pelu bi a se man dari ere lehin ti o pari ile iwe giga. Lehin na won lo si ile eko African Film and Drama Academy (AFDA), ile eko nipa fiimu[4]. Lehin wa igba na won pari eko nipa sisere ni Los Angeles campusi titi New York Film Academy.[1]
Ise Ise
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ziqubu bere ere sise ni odun 2011 ni pase fiimu Man on Ground, eleyi ti o je ki ise ise re sun si waju. Gegebi onkowe ati oludari ere, won ko, won si tun gbe ere kukuru meta jade fun ra won awon fimmu na ni: Out Of Luck, Subdued ati Between the Lines.[1]. Won ti ko ere fun awon fiimu South African television soap opera gege bi Isidingo, Rhythm City ati fun Is'Thunzi . Won ko pa ninu kiko, gbigbejade ati didari supernatural ere dirama eleya merin ti a mosi Emoyeni.[5]
Ni odun 2019, won shey oludari ere elesese MTV Shuga Down South.
Asayan ere
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role |
---|---|---|
2011 | Man on Ground | Zodwa |
2014 | Hard to get | Skiets[6] |
2015 | While You Weren't Looking | Shado |
2015 | Tell Me Sweet Something | Tashaka |
Awon itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 http://www.sowetanlive.co.za/entertainment/2015/02/06/the-rise-and-rise-of-thishiwe-ziqubu
- ↑ http://pulse.com.gh/events/amaas-2016-full-list-of-winners-at-2016-africa-movie-academy-awards-id5139637.html
- ↑ https://rosebankkillarneygazette.co.za/291318/mtv-shuga-souths-second-season-tackles-hard-hitting-issues/
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2020-04-05. Retrieved 2020-10-11.
- ↑ https://www.timeslive.co.za/tshisa-live/tshisa-live/2019-01-02-emoyeni-is-more-than-just-about-witchcraft/
- ↑ Helen Herimbi (10 March 2015). "A new girl Nox on Kilowatt’s door". e.tv. http://www.etv.co.za/news/2015/03/10/new-girl-nox-kilowatt-s-door. Retrieved 13 June 2016.