Jump to content

Thomas Brodie-Sangster

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Thomas Brodie-Sangster
Brodie-Sangster ní San Diego Comic-Con ọdún 2015
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kàrún 1990 (1990-05-16) (ọmọ ọdún 34)
London, England
Orúkọ mírànThomas Sangster
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́2001–present

Thomas Brodie-Sangster (tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1990)[1] jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Britain. Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Sam Love Actually (2003), Simon nínú Nanny McPhee (2005), Ferb nínú Phineas and Ferb (2007–2015), Jojen Reed nínú Game of Thrones (2013–2014), Newt nínú Maze Runner film (2014–2018), àti Benny Watts nínú eré Netflix tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ The Queen's Gambit (2020), èyí tí ó sì mú kí wọ́n yán mọ́ ara àwọn tí ó tó sí àmì ẹyẹ Primetime Emmy Award.[2][3]

Brodie-Sangster tún gbajúmọ̀ si nígbà tí ó ṣeré nínú àwọn eré bi Death of a Superhero (2011), Bright Star (2009), àti gẹ́gẹ́ bi Paul McCartney nínú Nowhere Boy (2009). Jake Murray Accused (2010–2012). Ó farahàn nínú eré Star Wars: The Force Awakens (2015), ó sì kópa gẹ́gẹ́ bi Whitey Winn nínú eré Netflix tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Godless (2017).

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Famous birthdays for May 16: Thomas Brodie-Sangster, David Boreanaz". United Press International, Inc. Retrieved 12 December 2020. 
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named winnet
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0