Thomas Edison
Tani Thomas Edison?
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Thomas Edison | |
---|---|
Edison as he appears at the National Portrait Gallery in Washington, D.C. "Genius is 1 percent inspiration, 99 percent perspiration." | |
Ọjọ́ìbí | Thomas Alva Edison Oṣù Kejì 11, 1847 Milan, Ohio, United States |
Aláìsí | October 18, 1931 West Orange, New Jersey, USA | (ọmọ ọdún 84)
Iṣẹ́ | Onihumo, okunrin akeko imo-jinle, onisowo |
Olólùfẹ́ | Àdàkọ:Igbéyawo Àdàkọ:Igbéyawo |
Àwọn ọmọ | Marion Estelle Edison (1873–1965) Thomas Alva Edison Jr. (1876–1935) William Leslie Edison (1878–1937) Madeleine Edison (1888–1979) Charles Edison (1890–1969) Theodore Miller Edison (1898–1992) |
Parent(s) | Samuel Ogden Edison, Jr. (1804–1896) Nancy Matthews Elliott (1810–1871) |
Àwọn olùbátan | Lewis Miller (Baba oko) |
Signature | |
Fáìlì:Thomas Alva Edison Ibuwolu.svg |


Thomas Alva Edison (February 11, 1847 – October 18, 1931) je oluda ati onisowo ara Amerika. O da awon ero dabi: ero agbohun, kamera aworan isipoda, ati gilobu ina. Thomas Edison ti da opolopo ohun, awon ohun ti Thomas Edison ti da, won ti ni ipa ti tobi lori abayé wa. Thomas Edison ti ran wa lowo lati se awon ohun ni ona ti o rorun gan. Thomas Edison ti sise pelu orisirisi akeko imo-jinle (sayensi) ati pelu orisirisi oniwadi. Thomas Edison ti da ilé imo-jinle akoko.
Thomas Edison ti dàgbà ni arin iwo oorun Amerika. Kutukutu ni ise re, o ti sise bi onise ero itewaya.[1] Ise yi, o ti ran òun lowo lati beere pelu kiikan re. Awa n wo Thomas Edison bi onihumo ti tobi gan ni gbogbo itan-akoole Amerika.
Thomas Edison bi omo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Eto eko ti Thomas Edison ti ni, ko ti poju, ni otito, o ti je diè-diè. Thomas Edison ti lo si ilé-iwe fun osu diè.Iyà re ti ko bawo ka, ko, ati se isiro sùgbon won ti je iyanilenu ati won ti ko ara re pelu awon iwe. [2]
Edison ti bèrè lati sise ni odun kutuktu, o ti je deedee lati se be. Nigba ti Thomas Edison ti ni odun metala, won ti bèrè lati je omokunrin ti iroyin. Nigba naa, Thomas Edison ti ta iwe iroyin ati súwìtì lori ojú-irin. Oju-irin yi, ti lo lati Port Huron si Detroit. Thomas Edison ti lo asiko ti opo lati ka awon iwe ti imo-jinle ati ilé-iwe. Thomas Edison ti ko bawo mu sise awon ẹrọ itẹwaya. Nigba ti Thomas Edison ti ni odun merindilogun, o ti mo bawo mu sise ero itewaya daradara ati o ti le sise bi okunrin ero itèwaya akoko kikun.
Idàgbàsokè ti ero itèwaya ti je igbese akoko lati bere, won ti ni iyika ti ibara eni soro[3] nitori naa ilé-isé ti bèrè lati fàgun kiakia ni apakan keji ni Ogorun Odun kokandinlogun. Nissi, Thomas Edison ti lé se ìrìn ajò, o ti lé ri orilè-èdè, ati jèrè iriri.
Thomas Edison ti je alagbawi fun agbara DC sùgbon, atileyin re fun agbara DC ti mu òun awon wahala pelu awon èniyan ti o ni atileyin fun agbara AC.[4]
Iwe iranti ti awon ise ati kiikan ti o tobi gan ti Thomas Edison:[5]
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Charles Batchelor ti lo imolè lati ya foto akoko bi ni itan akoole ati gbogbo ayé ni 1880. [6]
- 1868: agbohunsile itanna ti idibo
- 1874: seda ero itewaya ti le firanse ifiranse merin ni waya ni asiko kanna
- 1876: Edison bere lati sise lori atagba telifoonu ti erogba, gbohungbohun ti thomas ti da fun awon telifoonu
- 1877: seda phonograph (ohun ti igbasile awon ohun ati le mu sise fun awon èniyàn ti le gbo awon ohun)
- 1879: gilobu ina, Edison ti da èniyàn olokiki
- 1882: Edison ti lo eto itanna ti agbara lati fun ni awon ilé aadota mejo itanna ni Manhattan.
- 1891: Edison fi opolopo èniyàn han Kinetoscope ati Kinetograph, awon aseyori ti o tobi fun ilé-isé aworan-isipopada.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://en.wikipedia.org/wiki/Thomas_Edison
- ↑ https://www.nps.gov/edis/learn/historyculture/edison-biography.htm#:~:text=Edison%20had%20very%20little%20formal,improvement%20remained%20throughout%20his%20life.
- ↑ https://www.nps.gov/edis/learn/historyculture/edison-biography.htm#:~:text=Edison%20had%20very%20little%20formal,improvement%20remained%20throughout%20his%20life.
- ↑ https://www.autodesk.com/design-make/articles/thomas-edison-accomplishments
- ↑ https://www.autodesk.com/design-make/articles/thomas-edison-accomplishments
- ↑ https://www.autodesk.com/design-make/articles/thomas-edison-accomplishments