Threads
Ìrísí
Screenshot | |
URL | threads.net |
Registration | Required |
Available language(s) | |
Owner | Meta Platforms |
Current status | Active |
Thread jẹ́ ìkànnì ayélujára tí ó jẹ́ ìní ilé isé Meta. Ó dà bi àwọn ìkànnì ayélujára bi Twitter: Àwọn tí ó wà lórí ìkànnì náà le fi ọ̀rọ̀ àti fọ́tò léde, wọ́n le fi èsì sí ọ̀rọ̀. Ìkànnì náà wà lórí iOS àti Android. Àwọn tí ó ń lò ó dé iye mílíọ̀nù ọgọ́rin ní àárín wákàtí méjìdínládọ́tá.[1][2][3]
Wọ́n fi ìkànnì Threads lélẹ̀ ní ọjọ́ karùn-ún oṣù keje ní ọgọ́rùn-ún orílẹ̀ èdè, àwọn orílẹ̀ èdè bi United States, United Kingdom, Australia, New Zealand, Canada, àti Japan.[4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Threads App Reaches 80 Million Users As Twitter Threatens Lawsuit" (in en). Search Engine Journal. 2023-07-07. https://www.searchenginejournal.com/threads-instagram-app/490812/.
- ↑ Roth, Emma (2023-07-05). "Instagram’s Threads: all the updates on the new Twitter competitor" (in en-US). The Verge. https://www.theverge.com/2023/7/5/23784480/threads-instagram-meta-news-twitter-competitor.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:2
- ↑ "Threads launches in NZ: Facebook's new Twitter rival". 1 News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2023-07-07. Retrieved 2023-07-07.