Thucydides
Ìrísí
Thukydidis (Thucydides) (c. 460 BC – c. 395 BC) (Èdè Grííkì Ayéijọ́un: Θουκυδίδης [Thoukudídēs] error: {{lang}}: text has italic markup (help)) je Griiki olukoitan ati olukowe Itan Ogun awon ara Peloponesi, to so nipa ogun orundun 5 kJ larin Sparta ati Athens titi de odun 411 kJ. Thukydidis je mimo bi baba "itan onisayensi" nitori awon ona to lo lati sakojo idi ati igbeyewo nipa itori ati ifa lai menu ba ipa awon olorun, gege bo se je lilasile ninu ibere si ise re.[1]
Won tun pe bi baba eka-eko realisimu oloselu, to n fojuwo awon ibasepo larin awon orile-ede pe won da lori agbara kuku eto.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |