Tiffany Trump
Ìrísí
Tiffany Trump | |
---|---|
Trump speaking at the 2016 Republican National Convention | |
Ọjọ́ìbí | Tiffany Ariana Trump 13 Oṣù Kẹ̀wá 1993 West Palm Beach, Florida, U.S. |
Ẹ̀kọ́ | |
Political party | Republican |
Olólùfẹ́ | Michael Boulos (m. 2022) |
Parent(s) | Donald Trump Marla Maples |
Ẹbí | Trump |
Tiffany Ariana Trump (tí wọ́n bí ní October 13, 1993)[1] jẹ́ ọmọ kẹrin ti ààrẹ U.S ìgbà kan, èyí tí í ṣe Donald Trump. Tiffany sì ni ọmọ kan ṣoṣo tí ìyàwó kejì Donald bí.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Struyk, Ryan (April 11, 2016). "Trump Kids Eric and Ivanka Miss Deadline to Vote in NY GOP Primary". ABC News. Archived from the original on October 12, 2017. Retrieved October 11, 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)