Timi Dakolo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Timi Dakolo
Background information
Ọjọ́ìbíOṣù Kínní 20, 1981 (1981-01-20) (ọmọ ọdún 43)
Accra, Ghana
Ìbẹ̀rẹ̀Bayelsa State, Nigeria
Irú orinSoul music
Occupation(s)Singer
InstrumentsVocals
Years active2007–present
LabelsVirgin Records (UMG)
Websitetimidakolo.com

Timi Dakolo (tí a bí ní ọjọ́ ogún, oṣù kìíní, ọdún 1981) jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akọrin-kalẹ̀ àti agbórin-jáde.[1] Ó kópa nínú ìdíje Idols West Africa ní ọdún 2007, ó sì jáde pẹ̀lú ipò kìíní.[2] Lẹ́yìn aṣeyọrí rẹ̀ yìí, ó tẹwọ́bọ̀wé iṣẹ́ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ Sony BMG, ó sì gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn mìíràn.[3][4]

Àtòjọ àwọn orin rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Albums[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • 2011: "Beautiful Noise"
  • 2019: “Merry Christmas, Darling “

Singles[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • 2011: "There's a Cry"
  • 2011: "Great Nation"
  • 2014: "Iyawo Mi"
  • 2015: "Wish Me Well"[5]
  • 2016: "The Vow"
  • 2017: "Medicine"
  • 2018: "I Never Know Say"
  • 2019: "Merry Christmas Darling feat. Emeli Sande"
  • 2020: "Take" Ft. Olamide
  • 2021: "Everything (Amen)"

Àwọn àmì-ẹ̀yè rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • 2010: Hip Hop World Revelation of the Year – Nominated, during The Headies
  • 2015: Best Recording of the Year- Wish Me Well

References[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]