Tina Fey

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tina Fey
Fey ní ọdún 2022
Ọjọ́ìbíElizabeth Stamatina Fey
Oṣù Kàrún 18, 1970 (1970-05-18) (ọmọ ọdún 53)
Upper Darby Township, Pennsylvania, U.S.
Ẹ̀kọ́University of Virginia (BA)
Iṣẹ́
  • Actress
  • comedian
  • writer
  • producer
Ìgbà iṣẹ́1997–present
WorksFull list
Olólùfẹ́
Jeff Richmond (m. 2001)
Àwọn ọmọ2
AwardsFull list
Tina Fey
Medium
  • Television
  • film
  • theatre
  • books
Genres
Subject(s)

Elizabeth Stamatina "Tina" Fey ( /f/; tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1970) jẹ́ òṣerébìnrin, aláwàdà ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Fey wà lára àwọn tí ó ko eré NBC sketch comedy tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ Saturday Night Live láti ọdún 1997 títí di 2006. Òun ni ó sagbátẹ̀rù sitcom 30 Rock (2006–2013, 2020) àti eréNetflix tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ Unbreakable Kimmy Schmidt (2015–2020). Fey tún gbajúmò fún ipa rẹ̀ nínú àwọn eré bi Mean Girls (2004), Baby Mama (2008), Date Night (2010), Megamind (2010), Muppets Most Wanted (2014), Sisters (2015), Whiskey Tango Foxtrot (2016), Wine Country (2019), Soul (2020), àti A Haunting in Venice (2023).

Fey tí gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹyẹ bi àmì ẹyẹ Primetime Emmy mẹ́sàn-án, Golden Globe Awards mẹ́ta, àmì ẹyẹ Screen Actors Guild márùn-ún, àti àmì ẹyẹ Writers Guild of America méje. Ní ọdún 2008, Associated Press fún Fey ní àmì ẹyẹ AP Entertainer fún ọdún náà fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Sarah Palin ní SNL. Ní ọdún 2010, Fey tún gbà àmì ẹyẹ Mark Twain Prize for American Humor.

Ìpìlẹ̀ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Elizabeth Stamatina Fey ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Kàrún ọdún 1970[1][2]Upper Darby Township, Delaware County, Pennsylvania. Bàbá rẹ̀, Donald Henry Fey, wà lára àwọn tí ó fìgbà kan ja ogun ní orílẹ̀ èdè Korea, ó fìgbà kan jẹ́ adarí Yunifásítì ti Pennsylvania àti Yunifásítì Thomas Jefferson.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Monitor". Entertainment Weekly (Time Inc.) (1207): p. 29. May 18, 2012. 
  2. Mock, Janet. "Tina Fey Biography". People. p. 1. Archived from the original on March 29, 2011. Retrieved June 24, 2009.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)