Èdè Tiv

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Tiv language)
Tiv
Sísọ níGúúsù-Ìlàòrùn Nàìjíríà
Ọjọ́ ìdásílẹ̀1991
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀2,200,000
Èdè ìbátan
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3tiv

Tiv jẹ́ èdè tí wón so ní Nàìjíríà (ní àwọn Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé, Plateau, Tàràbà, Násáráwá àti Agbègbè Olúìlú Ìjọba Àpapọ̀ Abùjá) àti ní orílẹ̀-èdè Cameroon. Àwọn ènìyàn tí ó lé ní milionu márùn-ún ni ó ń sọ èdè náà. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn tí wón ń so èdè TIV wá láti Ìpínlẹ̀ Benue.

Ọkọ àti ìyàwó láti ẹ̀yà Tiv

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]