Tochukwu Oluehi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tochukwu Oluehi
Personal information
Ọjọ́ ìbí2 Oṣù Kàrún 1987 (1987-05-02) (ọmọ ọdún 36)
Ìga1.68 m
Playing positionGoalkeeper
Club information
Current clubMaccabi Kishronot Hadera F.C.
Number1
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2006–2010Bayelsa Queens F.C.
2011–2013Sunshine Queens F.C.
2013–2014Bobruichanka Bobruisk
2014–2015Rivers Angels F.C.
2016Medkila IL21(0)
2017–2020Rivers Angels F.C.
2020–2021Pozoalbense0(0)
2020–Maccabi Kishronot Hadera F.C.
National team
Nigeria women's national football team
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Tochukwu Oluehi jẹ elere agbabọọlu lobinrin orilẹ ede Naigiria ti a bini ọjọ keji, óṣu may ni odun 1987. Àrabinrin naa ṣere gẹgẹbi goalkeeper fun Rivers Angels[1]

Aṣeyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Tochukwu gẹgẹbi goalkeeper Rivers Angels kopa ninu Ere Tokyo Olympic 2020 nibi ti arabinrin naa si wa lara awọn ọgbọn agbabọọlu ninu idije na[2][3]
  • Tochukwu ti kopa lẹ mẹta ninu FIFA Cup Obinrin Agbaye, arabinrin na tun pegede ninu Championship Obinrin awọn Afirica ni ilu Namibia ni ọdun 2014[4].

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://www.celebsagewiki.com/tochukwu-oluehi
  2. https://guardian.ng/sport/football/oluehi-leads-30-falcons-to-camp-as-team-prepares-for-clash-with-algeria/
  3. https://punchng.com/i-knew-i-would-save-angels-oluehi/
  4. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-06-20. Retrieved 2022-05-23.