Jump to content

Tolulope Akande-Sadipe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tolulope Akande-Sadipe
Aṣojú ní ilé ìgbìmò Asòfin kékeré
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
2019
ConstituencyOluyole Federal Constituency
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí29 Oṣù Kẹta 1966 (1966-03-29) (ọmọ ọdún 58)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúẸgbẹ́ òsèlú APC
ProfessionOlóṣèlú

Tolulope Akande-Sadipe je òtòkùlú oloselu omobibi ìpínlè Oyo, orile-ede Naijiria tí a bi ní ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdun 1966. Òun ni óún se soju agbegbe Oluyole Federal Constituency ni Ile-igbimọ Aṣoju[1]. Ó jé omo egbe òsèlú All progressive Congress(APC).

Akande kékó gboyè ninú ìmò isiro(Accounting) ósì tèsíwájú láti gba àmì èye masters rè nínú ìmò International business management, osise pelu awon ilé-isé Dangote Group, GT bank plc(ní Nàìjíríà) àti àwon ilé-isé miràn ni America. [2] O darapo mó ìjoba ìpinlè Oyo ní osù kinni odun 2016, ó sì jé oluseto fun opolopo isé tí ijoba ìpínlè Oyo se. [3] Totulope wà lara àwon obinrin mejila(12) tó wà ní ilé igbimo asojú, awon tókù ní Taiwo Oluga, Khadija Bukar Abba Ibrahim, Boma Goodhead, Beni Butmak Lar, Onanuga Adewunmi Oriyomi, Aishatu Jibril Dukku, Ogunlola Omowumi Olubunmi, Zainab Gimba, Onuh Onyeche Blessing, Lynda Chuba Ikpeazu, Nkeiruka C. Onyejeocha. Tolulope dá ajo "Live abundantly" kalè láti ja fun ètó omo omode àti obinrin, láti mu kí iwe kika rorun fún àwon omo ti koni owo àti láti ran èdá lówó [4]

Totulope Sadife fé Dipo Sadipe.

  1. "Mrs. Tolulope Akande-Sadipe". 2021-12-03. Archived from the original on 2022-05-23. Retrieved 2022-05-22. 
  2. "Tolulope Akande Sadipe's biography, net worth, fact, career, awards and life story". ZGR.net. 2020-09-15. Retrieved 2022-05-22. 
  3. "About Us". 2021-12-03. Archived from the original on 2022-05-23. Retrieved 2022-05-22.