Jump to content

Tom Holland

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tom Holland
A picture of Tom Holland smiling towards the camera
Holland ní 2016 San Diego Comic-Con
Ọjọ́ìbíThomas Stanley Holland
1 Oṣù Kẹfà 1996 (1996-06-01) (ọmọ ọdún 28)
London, England
Ẹ̀kọ́BRIT School
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́2006–present
WorksRoles and awards
Parent(s)

Thomas Stanley Holland (tí a bí ní ọjọ́ kínní oṣù kẹfà ọdún 1996) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Britain. Ara àwọn àmì ẹyẹ rẹ̀ ni British Academy Film Award àti saturn awards mẹ́ta. Àwọn àtẹ̀jáde míràn ti pèé ní òṣèré tí ó gbajúmọ̀ jùlọ ní ìran rẹ̀.[lower-alpha 1]

Holland jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́sàn-án nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ erẹ́ ṣíṣe, ó darapọ̀ mọ́ ẹ̀kọ́ ijó kan nígbà náà, ọkàn lára àwọn oníjó sì kíyèsí, èyí mú kí ó ràn lọ́wọ́ láti fi ìfẹ́ hàn sí jíjẹ́ ara àwọn òṣèré nínú eré Billy Elliot the MusicalVictoria Palace Theatre. Holland bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣeré ní pere wu nígbà tí ó ṣeré nínú fíìmù The Impossible (2012) gẹ́gẹ́ bi ọ̀dọ́kùnrin tí ó sọnù sínú tsunami. Lẹ́yìn èyí, Holland tí ṣeré nínú àwọn eré bi How I Live Now (2013), In the Heart of the Sea (2015) àti Wolf Hall (2015).

Holland di gbajúmọ̀ káàkiri orílẹ̀ èdè nígbà tí ó ṣeré gẹ́gẹ́ bi Spider-Man/Peter Parker nínú eréMarvel Cinematic Universe (MCU) mẹ́fà, ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú Captain America: Civil War (2016). Ní ọdún tó tẹ̀le, Holland gba àmì-ẹ̀yẹ BAFTA Rising Star Award, ó tún ṣeré nínú Spider-Man: Homecoming, Far From Home (2019), No Way Home (2021), Uncharted (2022), The Devil All the Time (2020), Cherry (2021).

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named GQ
  2. "Tom Holland's 10 Best Roles (That Aren't Spider-Man)". Comic Book Resources. 10 April 2022. https://www.cbr.com/tom-holland-best-roles-not-spider-man/. 
  3. Langmann, Brady (21 February 2022). "'Uncharted' Doesn't Know What to Do With Tom Holland". Esquire. https://www.esquire.com/entertainment/movies/a39138436/tom-holland-uncharted-review-peter-parker-spider-man/. 
  4. Lucas, Robyn (13 December 2021). "Tom Holland on the highs and lows of being Spider-Man – and how Zendaya helped him to cope with fame". News24. Archived from the original on 8 May 2023. Retrieved 8 May 2023.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "Happy Birthday Friendly Neighborhood Spider Man: Tom Holland". The Statesman. 2 June 2022. https://www.thestatesman.com/entertainment/happy-birthday-friendly-neighborhood-1503077579.html. 


Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/> tag was found