Jump to content

Tosin Igho

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tosin Igho
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́AFDA, The School of motion picture medium
Iṣẹ́Film director
Gbajúmọ̀ fúnSeven (2019 Nigerian film) The Even. Nneka the pretty serpent 2020
Parent(s)Peter Igho
AwardsAfrica Magic Viewers Choice Award Winner

Tosin Igho jẹ́ olùdarí fíìmù àgbéléwò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ìgbésí-ayé àti iṣẹ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Tosin jẹ́ ọmọ olóòtú ètò NTA tó gbajúmọ̀, tí orúkọ rẹ ń jẹ́ Peter Igho.[1] Ó gba òye ẹ̀kọ́ nínú ìmọ Visual Effects láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti AFDACape Town, South Africa tí ó sì tún gba oyè bachelor's degree nínú ìmọ motion picture medium.[2][3] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olórin, tí ó sì tún jẹ́ olùdarí àwọn fídíò orin lóríṣíriṣi. Ó ti fìgbà kan jẹ́ olùdarí fídíò orin èyí tí àwọn gbajúmọ̀ olórin bíi Mo' Hits Records' D'banj, Terry G, Faze, Yung L, Aramide àti Sammie Okposo.[4]

Àwọn fíìmù tó ti ṣe

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó jẹ́ aṣàgbéjáde àgbà fún àwọn ètò bíi Once Upon A Time, Judging Matters, Love Come Back (2020-2022), I am Laycon.[2][1]

Ó jẹ́ olùdarí fíìmù Seven (2019), The Eve (2018), Nneka the Pretty Serpent (2020), Team Six (2021), bẹ́ẹ̀ sì ni ó ṣiṣẹ́ lórí fíìmù Suspicion (2023)

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 "Nollywood director, Tosin Igho set to launch films showcasing Nigeria". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-11-22. Retrieved 2022-07-20. 
  2. 2.0 2.1 "Here is why Tosin Igho is currently one of the leading movie directors in Africa". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-18. Retrieved 2022-07-20. 
  3. "Meet Nollywood leading movie director, Tosin Igho, flying Africa". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-16. Retrieved 2022-07-20. 
  4. ogunlami, yinka (2018-04-11). "This might be the most colourful Nollywood film you'll see in 2018". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-20.