Jump to content

Tracee Ellis Ross

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tracee Ellis Ross
Ross at the 2014 NAACP Image Awards
Ọjọ́ìbíTracee Joy Silberstein
29 Oṣù Kẹ̀wá 1972 (1972-10-29) (ọmọ ọdún 51)
Los Angeles, California, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gígaBrown University
Iṣẹ́Actress, model, comedian, television host
Ìgbà iṣẹ́1996–present
Parent(s)Robert Ellis Silberstein
Diana Ross
Àwọn olùbátan
Websitetraceeellisross.com/

Tracee Ellis Ross (oruko abiso Tracee Joy Silberstein; October 29, 1972) je osere, ologe, alawada ati olootu eto telifisan to gbajumo fun ere re bi Dr. Rainbow Johnson lori ere awada ile-ise telifisan ABC Black-ish.[1]

Tracee Ellis Ross je ikan ninu awon omo Diana Ross.