Jump to content

Trigonomẹ́trì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Fotothek df tg 0000230 Geometrie ^ Tirigonomẹ́tìrì.jpg

Igunwíwọ̀n (trigonometry) ni eka mathimatiiki to je mo kiko awon ifise pataki awon igun ati imulo won fun orisirisi isiro.