Tumi Morake

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Tumi Morake (bíi ni ọjọ́ kẹjìlélógún oṣù kejìlá ọdún 1081) jẹ́ òṣèré, agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati akọ̀wé ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà.[1][2][3][4] Ní ọdún 2018, ó jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ní ilé Áfríkà tí ó má gbé eré ẹ̀fẹ̀ rẹ sì orí Netflix.[5] Òun sì obìnrin àkọ́kọ́ tí ó ma ṣe atọkun fun ètò Comedy Central Presents ni ilẹ̀ Áfríkà.[6] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Wits University níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò dírámà.

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní oṣù keje ọdún 2005, ó darapọ̀ mọ́ àwọn tí ó má ṣe àwàdà àti ẹ̀fẹ̀. Láàárín àwọn ibi tí ó tí ṣe àwàdà ni Heavyweights Comedy Jam, Blacks Only, Have a Heart, Just Because Comedy Festival, The Tshwane Comedy Festival, The Lifestyle SA Festival àti Old Mutual Comedy Encounters.[7] Ó ti ṣe atọkun fun àwọn ètò bíi Our Perfect Wedding, Red Cake àti WTFTumi.[8] Òun ni ó kọ ìwé And Then Mama Said.[9][10] Ní ọdún 2012, ó gbà àmì ẹ̀yẹ Entertainer of the Year láti ọ̀dọ Speaker of Note Award.[11] Ní ọdún 2013, ó gba àmì ẹ̀yẹ Excellence in Comedy láti ọ̀dọ Mboko Women in Arts Award.[12] Ní ọdún 2016, ó gbà àmì ẹ̀yẹ aláwádà tó dara jù lọ láti ọ̀dọ YOU Spectacular Awards.[13]

Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Skin
  • Kota Life Crisis
  • Soul Buddyz
  • Izoso Connexion
  • High Rollers
  • Laugh Out Loud
  • Rockville
  • Soul Buddyz
  • The Queen
  • The Bantu Hour
  • Seriously Single[14]
  • Tumi or Not Tumi (Netflix)

Ìgbéyàwó[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Tumi jẹ́ ìyàwó fún Mpho Osie-Tuty, wọn sì ti bí ọmọ mẹ́ta.[15][16]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Kwach, Julie (2019-04-09). "Tumi Morake biography, husband, weight loss, family, book and comedy career". Briefly (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-02. 
  2. "Tumi Morake | TVSA". www.tvsa.co.za. Retrieved 2019-12-02. 
  3. "Tumi Morake Biography: Age, Family, Husband, Weight Loss, Book". ZAlebs (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-11-18. Retrieved 2019-12-02. 
  4. "Tumi Morake talks 'Comedians of the World on Netflix' and some... | IOL Entertainment". www.iol.co.za (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-02. 
  5. Lisa, Purity (2018-07-12). "Tumi Morake sets record as first African woman to have Netflix Special". Ghafla! South Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-02. 
  6. "Tumi Morake". Motsweding FM. Retrieved 2019-12-02.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Tumi Morake | TVSA". www.tvsa.co.za. Retrieved 2019-12-02. 
  8. "Tumi Morake Biography: Age, Family, Husband, Weight Loss, Book". ZAlebs (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-11-18. Retrieved 2019-12-02. 
  9. "Tumi Morake to release highly anticipated debut book". SowetanLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-02. 
  10. Magadla, Mahlohonolo (2018-09-12). "Tumi Morake releases her debut book". Channel (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-02. 
  11. "Tumi Morake". Motsweding FM. Retrieved 2019-12-02.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  12. "Tumi Morake". Motsweding FM. Retrieved 2019-12-02.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  13. "Tumi Morake Becomes First Woman To Win 'Comic of The Year' Award". Cosmopolitan SA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-09-07. Archived from the original on 2020-05-02. Retrieved 2019-12-02. 
  14. "'Seriously Single' Review: Netflix's South African Rom-Com Brings Fresh Energy to Genre". Indie Wire. Retrieved July 31, 2020. 
  15. Dyomfana, Bulelani (2019-11-28). "Tumi Morake and Mpho Osie-Tutu celebrate their 10-year anniversary". Channel (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-02. 
  16. "'My kids are traumatised but I thank God everyday we're safe' - Tumi Morake". TimesLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-02.