Tunde Folawiyo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Tijani Babatunde Folawiyo (tí a tún mò ís Tunde Folawiyo) jé omo orílé èdè Nàìjíríà onísòwò. O si tun je alase ati oludari Yinka Folawiyo Group.[1]. Gege bi Forbes se gbe jade, o ni iwon toto $650 million gege bi oun ini.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]