Tunji Braithwaite

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Tunji Braithwaite je oloselu omo ile Naijiria. Lọ́ọ́yà ni Dr T́únjí Braithwaite olóṣèlú sì ni Wọ́n bí Dr Braithwaite ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹ́sàn-án ọdún 1943. Òun ni ó dá Nigeria Advanced Party (NAP) tí wọ́n ti parẹ́ sílẹ̀. Ó gbé àpótí fún ipò Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà lábẹ́ ẹgbẹ́ Grassroots Democratic Advanced Movement (DAM).