Tutsi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tutsi
Àpapọ̀ iye oníbùgbé
2.5 million (Rwanda and Burundi)
Regions with significant populations
Rwanda, Burundi, Eastern Democratic Republic of the Congo
Èdè

Kirundi, Kinyarwanda, French, English

Ẹ̀sìn

Predominantly Roman Catholicism
Minority Islam

Ẹ̀yà abínibí bíbátan

Hutu, Twa

Tutsi jé eya kan lárà àwon olùgbé mẹta àwọn ènìyàn orílẹ̀ èdè Rwanda and Burundi ni apa arin Afrika. Ìyàtọ̀ díẹ̀ ló wà láàrìn àsà àwọn ará Tutsi àti Hutu.

Àgbẹ̀ àti Olùsìn maalu ni isẹ́ àárò abínibí àwọn ara Tutsi. Maálù jẹ́ ohun tí àwọn ará Tutsi fi máa ń fi agbára àti Ọlà wọn han, èyí ló sì mú àwọn ará Tutsi jẹ́ Olúborí nínú isẹ́ àgbẹ̀. Fun bí ẹ̀ẹ́dégbẹ̀ta ọdún sẹ́yin ni Tutsi ti ń se ìjọba lórí àwọn tókù.