Jump to content

Tuwo shinkafa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tuwon shinkafa
Tuwon shinkafa
TypeTuwo, swallow
Place of originNàìjíríà
Region or stateàríwá orílè-èdè Nàìjíríà
Associated national cuisineNigerian cuisine
Serving temperatureHot, Usually Rolled Up In Spherical Form
Main ingredientsiresi, àgbàdo tàbí jero
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Tuwon shinkafa jẹ ọ̀kan lára àwọn ounjẹ Naijiria ati Niger tí ó wá lati Niger ati apa ariwa orilẹ èdè Naijiria . O jẹ oúnjẹ tí wón ń fi iresi ṣe, tí wón sì ń fi ọbẹ̀ miyar kuka, miyar kubewa, ati miyar taushe jẹ Ona méjì ni wọ́n fi ń se oúnjẹ yìí, wón le fi Àgbàdo se(èyí tí wọ́n pè ní tuwon masara), wọ́n sì le fi ìyèfun oka sẹ́(èyí tí wọn ń pè ní tuwon dawa).