Jump to content

Tuwon shinkafa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tuwon shinkafa
Tuwon shinkafa
TypeTuwo, swallow
Place of originNigeria
Region or stateNorthern Nigeria
Associated national cuisineNigerian cuisine
Serving temperatureHot, usually rolled up in spherical form
Main ingredientsRice, maize or millet
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Tuwon Shinkafa jẹ́ òkèlè ìrẹsì Nàìjíríà àti ẹ̀yà Nàìjíríà láti Niger àti Àríwá Nàìjíríà.[1][2][3] Ó jẹ́ oúnjẹ tí wọ́n máa ń ṣe láti ara ìrẹsì tiwantiwa tí ó ti rọ̀ tí ó sì yi, tí wọ́n sì sábàá máa ń jẹ pẹ̀lú orísìírísìí ọbẹ̀ bí Miyar Kuka, Miyar Kubewa, àti Miyar Taushe.[4][5] Orísìí méjì ni wọ́n máa ń ṣe láti ara àgbàdo àti ọkà bàbà ni à ń pè ní Tuwon Masara and Tuwon Dawa, tẹ̀léńtèlé.[6][7][8]Ghana, Omo Tuo ni wọ́n ń pe Tuwon Shinkafa.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "How to make Tuwon Shinkafa (Rice Fufu)". All Nigerian Recipes. Retrieved 6 July 2015. 
  2. "Cuisine of Nigeria: Tuwo shinkafa". Trek Zone (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-04. 
  3. "Three Delicious Delicacies, North of the Niger". Google Arts & Culture (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-04. 
  4. Brown, Ed (2020-03-30). "How to Prepare Tuwo Shinkafa and Miyan Taushe". Royac Shop (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-04. 
  5. "Simple Way to Make Ultimate Tuwon shinkafa d miyar kuka | Quick and Easy Recipes". familycooking.pages.dev. Retrieved 2022-05-04. 
  6. "Tuwo Shinkafa (Tuwon Shinkafa) - made from Raw rice and also with Rice flour". Nigerian FoodTV. 23 August 2014. Retrieved 6 July 2015. 
  7. Eshemokha, Udomoh (2020-07-31). "TUWO MASARA: Health Benefits, How to prepare Tuwo Masara, Tuwo Masara Recipes" (in en-US). https://nimedhealth.com.ng/2020/07/31/tuwo-masara-health-benefits-how-to-prepare-tuwo-masara-tuwo-masara-recipes/. 
  8. "How to Make Tuwon Dawa: Nigerian Guinea Corn Fufu". 9jafoods (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-07-30. Retrieved 2022-05-04.