US Army School of Infantry
United States Army Infantry School tí ó wà ní ìlú Fort Benning ni Ìpínlẹ̀ Georgia jẹ́ ilé-ìwé tí ó wà fún kíkọ́ àwọn ológun ilẹ̀ Amerika, United States armed forces.
Ètò ilé-ìwé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]llé-ìwé náà pín sí ẹ̀ka oríṣiríṣi, bíi:
- Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàádọ́wàá
- Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kọkàndílọ́gbọ̀n
- Ọ̀wọ́ kìíní, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹrìndíláàádọ́ta
- Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàádọ́ta
- Ọ̀wọ́ kẹta, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàádọ́ta
- Ọ̀wọ́ kẹta, ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnléláàádọ́ta
- Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kejìdínláàádọ́ẁá
- Ọ̀wọ́ kìíní, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kọkàndínlógún
- Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun eleekokandinlogun
- Ọ̀wọ́ kìíní, Àwọn ọmọ-ogun àádọ́ta
- Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnléláàádóta
- Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kejìdínlọ́gọ́ta
Fún àwọn èèyàn to ṣẹ̀ṣẹ̀ wọlé, ọ̀wọ́ àwọn ọmọ-ológun ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàádọ́wàá àti ẹlẹ́ẹ̀kejìdínláàádọ́ẁá máa ń gba ẹ̀kọ́ fún ọ̀sẹ̀ méjìlélógún[1]. Àfojúsùn àwọn ọ̀wọ́ yìí ni láti ṣe ìyípadà fún àwọn ará-ìlú láti di ọmọ-ológun tó já fáfá, tó kúnjú òṣùwọ̀n, tó ní ìwà ọmọ-ológun, tó dúró ire, tó níwà gidi, tó sì ń ṣiṣẹ́ dédé kí wón ba lè nì ìtẹ́wọ́gbà sínú ẹgbẹ́ náà.
- Àwọn ọmọ-ológun ẹlẹ́ẹ̀kọkàndínláàádọ́ẁá[2]
- Ọ̀wọ́ kejì, ọmọ-ogun ìkọkànlá
- Ọ̀wọ́ kẹta, ọmọ-ogun ìkọkànlá
- Ọ̀wọ́ kẹta, ọmọ-ogun ìkọkànlélọ́gọ́rin
- Ìwé àwọn akọgun
- Akádẹmì àwọn ológun aláìnígbìmọ̀ ti Henry Caro[3]
- Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn ológun ti òfurufú[7]
- Ìdánilẹ́kọ̀ọ́awon ọmọ-ogun eleekerin
- Ile-iwe awon ọmọ-ogun (ti Benning)
- Ìdánilẹ́kọ̀ọ́awon ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀karùn-ún
- Ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun (ti Mountain)
- Ìdánilẹ́kọ̀ọ́awon ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹfà
- Ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun (ti inú-irà)
- Ọ̀wọ́ àwọn ọmọ-ogun kìíní, Ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kejelélẹgbẹ̀fà
- Ilé-ìwé àwọn ajagun ti orí òfurufú
- Ilé-ìwé àwọn jumpmaster
- Àwon ọmọ Silver-wings
- Ìdánilẹ́kọ̀ọ́awon ọmọ-ogun eleekerin
- Adarí ajagun àpapọ̀
Àwọn ọmọ-ogun tó ti parí ẹ̀kọ́ ìpìlẹ̀ fún àwọn adarí máa ń lọ sí ọ̀wọ́ kejì láti gba Ìdánilẹ́kọ̀ọ́. Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ yìí wà fún ìgbaniníyànjú àti ẹ̀kó tó yè koro, kí wọ́n ba lè nímọ̀ nípa ìbọn lílò àti ìmọ̀ọ́ṣe nìgbogbo ọ̀nà.
Ọ̀wọ́ àwọn ọmọ-ogun yìí tún máa gbé Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kalẹ̀ fún ìmọ̀ níní nínu ogun orí òfurufú àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Adarí ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Adarì ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun máa ń jẹ́ olórí àti olùdarí ilé-ìwé yìí.[8]
No. | Àwòrán | Orúkọ | Ìbẹ̀rẹ̀ | Òpin |
---|---|---|---|---|
1 | Colonel Henry E. Eames | 5 October 1918 | 22 April 1919 | |
2 | Major General Charles S. Farnsworth[9] | 22 April 1919 | 31 July 1920 | |
3 | Brigadier General Walter H. Gordon | 1 August 1920 | 8 November 1923 | |
4 | Brigadier General Briant H. Wells | 9 November 1923 | 8 March 1926 | |
5 | Brigadier General Edgar T. Collins | 9 March 1926 | 1 May 1929 | |
6 | Brigadier General Campbell King | 2 May 1929 | 31 May 1933 | |
7 | Brigadier General George H. Estes | 1 June 1933 | 30 September 1936 | |
8 | Brigadier General Asa L. Singleton | 1 October 1936 | 31 August 1940 | |
9 | Major General Courtney Hodges | 1 September 1940 | 3 March 1941 | |
10 | Major General Omar N. Bradley | 4 March 1941 | 10 February 1942 | |
11 | Major General Leven C. Allen | 11 February 1942 | 18 September 1943 | |
12 | Major General Charles H. Bonesteel Jr. | 19 September 1943 | 27 June 1944 | |
13 | Major General Fred L. Walker | 28 June 1944 | 11 July 1945 | |
14 | Major General John W. O'Daniel | 12 July 1945 | 1 July 1948 | |
Major General John W. Foss[10] | 1983 | 1985 | ||
Major General Kenneth C. Leuer[11] | 1987 | 1989 | ||
47 | Major General Benjamin Freakley[12] | 2003 | 2005 | |
48 | Major General Walter Wojdakowski[13] | 2005 | 2008 | |
49 | Major General Michael Barbero[13] | 2008 | 2009[14] | |
50 | Major General MIchael Ferriter[15] | 2009 | 2009 | |
51 | Brigadier General Bryan Owens[16] | 2009 | 2011 | |
52 | Brigadier General Walter E. Piatt[17][18] | 2011 | 2012 | |
53 | Brigadier General David B. Haight[19] | 2012 | 2013 | |
54 | Colonel Robert E. Choppa[20] | 2013 | 2014 | |
55 | Brigadier General James E. Rainey[21] | 2014 | 2015 | |
56 | Brigadier General Peter Jones[22] | 2015 | 2017 | |
57 | Brigadier General Christopher T. Donahue[23] | 2017 | 2018 | |
58 | Colonel Townley R. Hedrick[24] | 2018 | 2018 | |
59 | Major General David M. Hodne [24] | 2018 | 2021 | |
60 | Brigadier General, Larry Q. Burris Jr.[25] | 2021 | Current |
Àwọn ìtọkasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 22-Week One Station Unit Training Archived 10 November 2011 at the Wayback Machine.
- ↑ Staff (n.d.). "199th Infantry Brigade". www.benning.army.mil. United States Army. Archived from the original on 2 February 2021. Retrieved 16 January 2021.
- ↑ Staff (n.d.). "Henry Caro Noncommissioned Officer Academy". www.benning.army.mil. United States Army. Archived from the original on 19 March 2016. Retrieved 21 March 2016.
- ↑ Staff (n.d.). "Maneuver Senior Leaders Course". www.benning.army.mil. United States Army. Archived from the original on 18 January 2021. Retrieved 16 January 2021.
- ↑ Staff (n.d.). "Infantry Advanced Leaders Course". www.benning.army.mil. United States Army. Archived from the original on 12 November 2020. Retrieved 16 January 2021.
- ↑ Warrior Leaders Course[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Staff (n.d.). "Airborne and Ranger Training Brigade". www.benning.army.mil. United States Army. Archived from the original on 11 March 2022. Retrieved 21 March 2016.
- ↑ "Office of the Chief of Infantry". United States Army Maneuver Center of Excellence. United States Army. 2 August 2012. Archived from the original on 31 January 2013. Retrieved 2 February 2013.
- ↑ Emerson, William K. (2004). Marksmanship in the U.S. Army: A History of Medals, Shooting Programs, and Training. University of Oklahoma Press. p. 101. ISBN 9780806135755. https://books.google.com/books?id=OdHtJ9-jCsIC&q=1st+%22Chief+of+Infantry%22+Farnsworth&pg=PA101. Retrieved 2 February 2013.
- ↑ "Army's chief of infantry will take over Ford Bragg". Star-News. Associated Press. 26 December 2009. https://news.google.com/newspapers?id=KklOAAAAIBAJ&pg=3875%2C8158823.
- ↑ "Fort Benning has always been Kenneth Leuer's home away from home". Columbus Ledger-Enquirer. Columbus Ledger-Enquirer. 28 October 2018. https://www.ledger-enquirer.com/news/local/article220685600.html.
- ↑ "Lieutenant General Benjamin C. Freakley" (PDF). ArmyEdSpace.com. United States Army. Retrieved 10 February 2013.
- ↑ 13.0 13.1 Bennett, Doraine (2008). "A Retrospective: MG Walter Wojdakowski, Chief of Infantry, August 2005 – November 2008". Infantry Bugler (National Infantry Association): 8–9. ISSN 1933-6225. Archived from the original on 27 August 2011. https://web.archive.org/web/20110827103532/https://www.infantryassn.com/Bugler%20issues/Winter_2008.pdf. Retrieved 10 February 2013.
- ↑ Little, Vince (5 June 2009). "CG reflects on tenure at Fort Benning". The Bayonet. United States Army. Retrieved 10 February 2013.
- ↑ Sitter, Bridgett (22 September 2009). "Leaders discuss future of Infantry, Armor". MCOE Public Affairs. United States Army. Retrieved 10 February 2013.
- ↑ Little, Vince (8 June 2011). "Chief of Infantry bids farewell to Benning". The Bayonet. United States Army. Retrieved 2 February 2013.
- ↑ Àdàkọ:Cite AV mediaÀdàkọ:Cbignore
- ↑ Little, Vince (3 August 2011). "Post hails new chief of Infantry". News Archive. United States Army. Retrieved 2 February 2013.
- ↑ Ben Wright (2 August 2012). "Fort Benning announces new commanders for Infantry and Armor Schools". Columbus Ledger-Enquirer. Archived from the original on 21 September 2013. https://web.archive.org/web/20130921055732/http://www.ledger-enquirer.com/2012/08/02/2144190/fort-benning-announces-new-commanders.html.
- ↑ "New Infantry chief takes command". The Bayonet. 4 December 2013. Archived from the original on 4 March 2016. https://web.archive.org/web/20160304002220/http://www.thebayonet.com/2013/12/04/513581/new-infantry-chief-takes-command.html.
- ↑ "Fort Benning welcomes new infantry chief and commandant". Columbus Ledger-Enquirer. 30 July 2014. Archived from the original on 17 October 2014. https://archive.is/20141017023259/http://www.ledger-enquirer.com/2014/07/30/3224831_fort-benning-welcomes-new-infantry.html.
- ↑ "Fort Benning to welcome new infantry chief Brig. Gen. Peter Jones". Columbus Ledger-Enquirer. 24 September 2015. http://www.ledger-enquirer.com/news/local/military/article36455706.html.
- ↑ "Brig. Gen. Donahue is 57th chief of infantry at Fort Benning". Columbus Ledger-Enquirer. 15 August 2017. http://www.ledger-enquirer.com/news/local/military/article167426392.html.
- ↑ 24.0 24.1 Gatchell, Bryan (3 August 2018). "New Commandant Takes Responsibility of US Army Infantry School". U.S. Army. https://www.army.mil/article/209432/new_commandant_takes_responsibility_of_us_army_infantry_school.
- ↑ "Soldier Lethality CFT welcomes new director". 2021-08-12.