Jump to content

Uduak Ekpo-Ufot

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Uduak Ekpo-Ufot jẹ́ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà tó sì jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tó ń ṣojú ẹkùn ìpínlẹ̀ Etinan ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpìpínlẹ ti Akwa Ibom lọwọlọwọ [1] [2] O je omo egbe Peoples Democratic Party . [3]