Jump to content

Umaru Abdullahi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Umaru Abdullahi
President of the Nigerian courts of appeals
In office
1999–2009
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1939-11-30)30 Oṣù Kọkànlá 1939
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNon partisian

Umaru Abdullahi (born November 30, 1939) jẹ́ adájọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Ààrẹ tẹ́lẹ̀ ti àwọn ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ní Nàìjíríà.[1]


Íse rẹ gẹgẹ bí olófin

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Justice Umaru was Call to the bar ni ọdún 1968 a sì Yàn gẹgẹ bí ọkan lára àwọn alága Nigerian courts of appeal ni ọdún 1983 gẹgẹ bí adájọ .[2][3] Ni odún 1987, a gbè ló sì ilú Kastina State láti je olùrànlọwọ to dá ilẹ idajo ìpínlè ni ọdún mẹta kọja,a fí je oyè àrè ile ìdájọ ko témi lọrùn, A Yàn gẹgẹ bí President of the Nigerian courts of appeals, ipò tí o di mú fún ọdún mẹwa láti 1999 Títí dé 2009 a sì ṣí ní ipò fún Ayo Salami a tí kò ìwé nípa ìgbé ayé rẹ tí àkòrí rẹ je about , 'Once Upon Umaru' by Ibe Ikwechegh. Justice Abdullahi o jẹ oye é ni ti ọ niyi of Walin Hausa .[4][5]



  1. Fasua, Tope (2007-12-18). "Nigerian News, Articles, Current Events, & Musings". NigerianMuse. Archived from the original on 2022-02-04. Retrieved 2022-02-08. 
  2. "Justice Umaru Abdullahi's Court of Appeasement, Corruption and Confusion". Sahara Reporters. Retrieved 29 April 2015. 
  3. "Court of appeal, Nigeria". courtofappeal.com. Archived from the original on 29 April 2015. Retrieved 29 April 2015. 
  4. "CJN Versus President, Court Of Appeal: Hon. Justice Umaru Abdullahi Report; Who Lied On Oath?". Sahara Reporters. Retrieved 29 April 2015. 
  5. "Justice Umaru Abdullahi - DailyPost Nigeria". DailyPost Nigeria. Retrieved 29 April 2015.