Jump to content

Ume Mathias

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ume Mathias jẹ olóṣèlú ọmọ ile-igbimọ aṣofin orilẹ-ede Nàìjíríà ti o wa ni Ile-igbimọ Aṣofin Ìpínlẹ̀ Abia ti o nsójú Umunneochi lati ọdun 2023. [1] Mathias bori labẹ Labour Party . [2]