Ummi Ibrahim

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


Ummi Ibrahim
Ọjọ́ìbí1987 (ọmọ ọdún 36–37)
Borno State
Ọmọ orílẹ̀-èdè Nigeria
Iṣẹ́Kannywood actress, musician, business woman
Ìgbà iṣẹ́2006 – present

Ummi Ibrahim jẹ́ òṣèrébìrin Kannywood (An Hausa Language Cinema) tó di olókìkí nínú fíìmù Jinsi níbi tí ó ti ní orúkọ rẹ̀ ní Zeezee.[1][2]

Iṣẹ́ Rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àríyànjiyàn wà nípa òṣèré náà ní ilé-iṣẹ́ náà bí ó ṣe sọ pé òun lòún ga jùlọ. Èyí fa ifarapa láàrín àwọn ẹlẹ́gbẹ́ rẹ̀ láti ìgbà tí wọ́n ti ríi kẹ́hìn ní Kannywood ní ọdún 2006. [3]

Àwọn Fíìmù Rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Jinsi[2]
  • Flag of Love
  • Yan uwa
  • Gambiza
  • Gender

Àwọn Ìtọ́ka Sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Online, Tribune (20 September 2017). "6 High-flying Kannywood actresses". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 August 2022. 
  2. 2.0 2.1 "Zee-Zee: The rise and rise of Jinsi queen". www.thenigerianvoice.com. Retrieved 8 August 2022. 
  3. Lere, Mohammed (29 April 2017). "Supremacy Tussle in Kannywood: Umma Shehu blasts Ummi ZeeZee, says she's a small fry". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 August 2022.