Umo Eno

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Umo Eno
Governor of Akwa Ibom
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 May 2023
DeputyAkon Eyakenyi
AsíwájúUdom Emmanuel
Akwa Ibom State Commissioner for Lands and Water Resources
In office
2021–2022
GómìnàUdom Emmanuel
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí24 Oṣù Kẹrin 1964 (1964-04-24) (ọmọ ọdún 60)
Nsit-Ubium, Eastern Region, Nigeria (now in Akwa Ibom State)
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeoples Democratic Party
Alma materUniversity of Uyo
Occupation
  • Politician
  • businessman

Umo Bassey Eno tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹrìnlélógún oṣù kẹrin ọdún 1964, jẹ́ olùṣọ́ àgùtàn ilé-ìjọsìn All Christain Ministary International àti olóṣèlú tí ó tún jẹ́ gómìnà ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom nínú ìdìbò tó wáyé ní ọdún 2023., ó sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1][2] Òun ni kọmíṣánà tẹ́lẹ̀ rí fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀ àti omi àlùmọnì fún ìpínlẹ̀ Akwa Ibom. [3][4]

Ibẹ̀rẹ̀ ayé ati ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹrìnlélógún oṣù kẹrin ọdún 1964, ní ìlú rẹ̀ Ikot Ekpene Ìró tí ó wà ní abẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Nsit-Ubium.[5] Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Local Authority Primary School tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó, níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí ẹ̀kọ́ akọ́bẹ̀rẹ̀ [6] He attended Local Authority primary school in Lagos State, where he got his first school leaving certificate.[7] Ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndìrì ti St. Francis tí ó wa ní ilú Eket tí ó sì parí ìpele ẹ̀kọ́ yí ní Victoey High School tí ó wà ní Ìkẹjà ní ípínlẹ̀ Èkó .[7] Ó gba ìwé-ẹ̀rí ẹ̀kọ́ agba jáde nínú ìmọ̀ Ìbáṣepọ̀ Àwùjọ ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì Uyo tí ó sì gba ìwé ẹ̀rí Masters jáde nínú ẹ̀ka ìmọ̀ yí kan náà.[8]

Iṣẹ́nṣe rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n gbàá sisẹ́ ní ilé-iṣẹ́ Union Bank lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ sẹ́kọ̀ndìrì rẹ̀ ṣáájú kí ó tó lọ ṣiṣẹ́ ní ilé-iṣẹ́ Bertola Machine Tools Nigeria Limited àti Norman Holdings Limited, níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá àgbà ṣáájú kí ó tó lọ dá ilé-iṣẹ́ Royalty Group tí ó jẹ́ olùdásílẹ̀ rẹ̀.[8] Wọ́n yànán sí ipò kọmíṣánà fún ọ̀rọ̀ ilẹ̀ ati omi àlùmọ́nì ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ní ọdún 2021 lábẹ́ gómìnà Udom Emmanuel[9][10][11] Ó kọ̀wé dupò náà sílẹ̀ láti díje du ipò Gómìnà ní Ìpínlẹ̀ náà ní ọdún 2023. [12][13]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Online, Tribune (2023-03-19). "PDP’s Umo Eno wins Akwa Ibom guber election with wide margin". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-20. 
  2. Vanguard (2023-03-19). "Breaking: INEC declares PDP’s Umo Eno winner of Akwa Ibom guber poll". Vanguard. Retrieved 2023-03-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "11 things we know about Gov Emmanuel’s preferred successor, Eno". www.premiumtimesng.com. Retrieved 2023-03-20. 
  4. "Pastor Umo Eno Marks 50th Birthday". 2014-05-10. https://www.channelstv.com/2014/05/10/pastor-umo-eno-marks-50th-birthday/amp/. 
  5. Rapheal (2023-03-17). "Decision Day 2023: Those who will be governors". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-20. 
  6. Rapheal (2023-03-17). "Decision Day 2023: Those who will be governors". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-20. 
  7. 7.0 7.1 "Umo Eno… Barracks Boy who wants to be governor". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-03-11. Archived from the original on 2023-03-20. Retrieved 2023-03-20. 
  8. 8.0 8.1 Rapheal (2022-05-23). "Bassey Umo Eno: Barracks boy you did not know". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-20. 
  9. "Udom Emmanuel swears in four commissioners, five perm secs". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-01-03. Retrieved 2023-03-20. 
  10. "Udom swears in new commissioners, perm secretaries - Businessday NG". businessday.ng. Retrieved 2023-03-20. 
  11. Anthony, Lovina (2021-01-11). "APC stalwart congratulates Gov.Emmanuel's new appointees, warns against politics of prejudice". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-20. 
  12. Online, Tribune (2022-03-24). "Akwa Ibom Assembly clears 6 Commissioner-nominees for swearing-in". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-20. 
  13. THEWILL, Udeme Utip. "Gov Udom Sacks Six Commissioners Including His Preferred Successor – THEWILL NEWS MEDIA" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-20.