Oníṣe:Adesunmisola2020
Ìrísí
Gírámà èdè Yorùbá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Anì àwon ìsọ̀rí ọ̀rọ̀ gírámà ní èdè yorùbá.ìsọ̀rí ọ̀rọ̀ ni a tun le pe ni ẹ̀yà ti a pin ẹyọ ọ̀rọ̀ kookan ti o di gbólóhùn ti si tun ni ìtumò kikun.
==ìsọ̀rí ọ̀rọ̀ gírámà èdè yorùbá==
Orísi gírámà èdè yorùbá ló wà
- òrò orúko
- òrò ìse
- òrò àsopọ̀
- òrò àpèjúwe
- òrò àpónlé
- òrò arópò orúko
7
- òrò atókùn
- òrò arópò afarajórúko [1]
Àwọn ìtọ́kasì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Dayo Akanmu et al. {2019} Gírámà èdè yorùbá àti ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀. Ìbàdàn, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Mestak Publisher